Skip to content
حصن المسلم من أذكار الكتاب والسنة

حصن المسلم من أذكار الكتاب والسنة

atipe a nsadi Olohun kuro nibi awon aburu emi wa, ati awon aburu ise wa, eniti Olohun ba ti fi mona ko si eniti o le so o nu, atipe entiti Olohun ba sonu ko si eniti o le fi mona, ki ike Olohun ati ola Re maa ba a ati awon ara ile re ati awon saabe re, ati eniti o ba tele won pelu daada titi di ojo esan, ki Olohun si se ola fun won ni opolopo ni eyin igba na:

0%
Font size