112 : 4
وَلَمۡ يَكُن لَّهُۥ كُفُوًا أَحَدُۢ
Kò sì sí ẹnì kan kan tí ó jọ Ọ́.”
Explanation & meanings · 1
- Àwọn kan máa ń ké “Ƙul huwa-llāhu” mẹ́ta fún òkú mùsùlùmí. Nígbà mìíràn, wọ́n lè ké òdidi al-Ƙur’ān fún un. Ìwọ̀nyí kò tọ sunnah rárá. Sūrah al-Haṣr; 59:10 ti fún wa ní àdúà tó jẹmọ́ òkú àti alààyè.