Ìwé-ìmọ̀ Àkóónú Ẹ̀sìn Islam
Ṣàwárí Àwọn Ẹ̀ka
Rìn kiri nínú àwọn àkójọpọ̀ ìmọ̀ wa tí ó gbòòrò
Àwọn Iṣẹ́ Ẹ̀kọ́ Pàtàkì
Àṣàyàn àwọn ohun èlò Islam tí ó jẹ́ tòótọ́
Bí Anabi - kí ikẹ àti ọla Ọlọ́hun máa bá a - ṣe n kirun.
Ìwé 'Kayfiyyatu ṣalātin Nabiyy ﷺ ( Bí anọbi ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ máa bá ) ni Ọlọla wa Olumọ agba Abdul Azeez ọmọ Bāz - ki Ọlọhun kẹ ẹ - tí ko àsàyàn ọrọ ṣe lórí irun Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a -, sínú rẹ, pẹ̀lú ọ̀nà ìgbékalẹ̀ tí ó rọrùn àti ìlànà tí ó péye, tí ó ní ìpìlẹ̀ nínú àwọn ìpìlẹ ọrọ tí ó jẹ́ ododo, láti jẹ́ amọ̀nà fún Musulumi nínú irun rẹ̀. Ó sì ti ṣàlàyé àwọn òpó irun kíkí, àwọn Sunna rẹ̀, àti àwọn ìrísí rẹ̀ nínú rẹ̀, bẹ̀rẹ̀ láti orí alùwàlá títí dé orí Tasliim ( pipari irun pẹlu salaman , nígbàtí ó pa ẹ̀rí pọ̀ mọ́ àlàyé, tí ó n pèpè sí títẹ̀lé Anabi - ki ikẹ ati ọla…
Ìsopọ̀ Tí Ó Rọrùn
API alágbára tí ó ń jẹ́ kí àwọn olùgbéjáde kọ́ àwọn ohun èlò wọn lórí ibi ìpamọ́ dátà wa.
Àtìlẹ́yìn Èdè Púpọ̀
Ìtumọ̀ ojú-ẹsẹ̀ àti àkóónú ní èdè tí ó ju 100 lọ kí iṣẹ́-ìránṣẹ́ náà lè dé ọ̀dọ̀ gbogbo ènìyàn.
Àkóónú Gbígbòòrò
A ní àkóónú tí ó pọ̀ gan-an, tí ó bo ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun èlò tí a ń béèrè fún, a sì ń gbèrò láti tẹ̀ ẹ́ jáde ní gbogbo èdè àgbáyé.
Àwọn Orísun Tí A Ti Fọwọ́sí
Gbogbo àwọn ohun èlò tí ó wà níbẹ̀ ń gba àyẹ̀wò líle koko láti rí i dájú pé orísun àti àkóónú péye.