الشهادتين
Ti o ba fẹ wọ inu Islam, o gbọdọ sọ ijẹri ti o nbọ yii pẹlu ohùn tí eeyan ma gbọ, waa si gbọ itumọ rẹ ye, waa si ni igbagbọ si i: Mo gba lododo wipe kosi ẹniti ijọsin ododo tọsi ayaafi Allah (awọn gbolohun yii tumọ si pe kosi enikankan ti o lẹtọ si ijọsin ayaafi Allah), Mo si gba lododo wipe dajudaju anabi Muhammad ojiṣẹ Allah ni, ati pe dajudaju anabi Isa ọmọ Maryam ẹrusin Allah ati ojiṣẹ Rẹ ni.

Mo gba lododo wipe kosi ẹniti ijọsin ododo tọsi ayaafi Allah, mo si gba lododo wipe dajudaju anabi Muhammad ojiṣẹ Allah ni.