Skip to content
Nnkan ti kò yẹ kí Musulumi ma mọ ọn nípa rẹ̀

Nnkan ti kò yẹ kí Musulumi ma mọ ọn nípa rẹ̀

Tira (Nnkan ti kò yẹ kí Musulumi ma mọ ọn nípa rẹ̀) jẹ́ tira pataki kan, tí a fi tàdáà ìmọ̀ àti àlàyé tó yanrannti kọ àwọn ọ̀rọ̀ inú rẹ̀, ó kó ohun tí Musulumi kò gbọdọ̀ má mọ̀ jọ sínú gẹgẹbi àwọn ìpìlẹ̀ adisọkan, àti àwọn òfin Islam, àti àwọn ẹwa ìwà rere, ní ọ̀nà tí ó péye, tí ó n tan ìmọ́lẹ̀ sí àwọn ojú inú, tí àwọn ọkàn sì n rí ifarabalẹ̀ látara rẹ̀, ó n tọ́ òye sọ́nà, ó sì n tún iṣẹ́ ṣe, nítorí náà, ó jẹ́ kọ́kọ́rọ́ ìgbàlà ní òdodo, àti amọ̀nà fún arìnrìn-àjò ní àwọn ojú ọ̀nà itẹle aṣẹ Ọlọhun àti ìmọ̀.

Èdè: lang_yo
Ẹni tí ó pèsè: Ìgbìmọ̀ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ lábẹ́ ìdarí ati ìṣàkóso àwọn olùmójútó ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ní Mọ́ṣáláṣí Haram Makkah àti Mọ́ṣáláṣí Anabi.
Ẹ̀yà: 3.1

These files are generated automatically from the book's text; their layout may differ from the printed edition.

0%
Font size