Skip to content
البَقَرَة /

Ẹsẹ 152

2 : 152

Ẹsẹ 152 of البَقَرَة (2 : 152). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

البَقَرَة Àwọn Ẹsẹ 286
2 : 152

فَٱذۡكُرُونِيٓ أَذۡكُرۡكُمۡ وَٱشۡكُرُواْ لِي وَلَا تَكۡفُرُونِ

nítorí náà, ẹ rántí Mi, Kí N̄g rántí yín. Ẹ dúpẹ́ fún Mi, ẹ má ṣàì moore sí Mi.

Explanation & meanings · 1
  1. “Ìrántí Allāhu” láti ọ̀dọ̀ ẹ̀dá sí Ẹlẹ́dàá ni àwọn iṣẹ́ ìjọ́sìn. Àmọ́ “Ìrántí Allāhu” láti ọ̀dọ̀ Allāhu Ẹlẹ́dàá sí ẹ̀dá ni àwọn ẹ̀san iṣẹ́ ìjósìn.