Skip to content

Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n sọ laaarin iforikanlẹ mejeeji pé: Robbi igfir liy, Robbi igfir liy”.

Lati ọdọ Huzeifah- ki Ọlọhun yọnu si i-:

Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n sọ laaarin iforikanlẹ mejeeji pé: Robbi igfir liy, Robbi igfir liy”.

أَنَّ النَّبِيَّ صَلَّى اللَّهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ كَانَ يَقُولُ بَيْنَ السَّجْدَتَيْنِ: «رَبِّ اغْفِرْ لِي، رَبِّ اغْفِرْ لِي».

Baba Daud ati Nasaa'iy ati Ọmọ Maajah ati Ahmad ni wọ́n gba a wa
O ni alaafia
Àlàyé

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n sọ nibi ijokoo laaarin iforikanlẹ mejeeji pé: Robbi igfir liy, Robbi igfir liy, o si maa n paara rẹ. Ìtumọ̀ Robbi igfir liy ni pé: Ki ẹru wa lati ọdọ Oluwa rẹ lati pa awọn ẹṣẹ rẹ rẹ ki O si bo awọn aleebu rẹ.

Ìtumọ̀ àwọn gbólóhùn

...:

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

Ṣíṣe adura yii lofin laaarin iforikanlẹ mejeeji nibi irun ọran-anyan ati naafila.

Ṣíṣe pipaara sisọ gbolohun: Robbi igfir liy lofin, ati pe iye igba ti o jẹ dandan ni ẹẹkan.

Àwọn ìwé ìwádìí

Tira Sunanu ti baba Daud (2/ 154) (874).

Tira Sunanu ti An-Nasaaiy (2/ 231) (1145).

Tira Sunanu ti Ọmọ Maajah (2/ 64) (897).

Tira Musnad ti Ahmad (38/ 392) (23375).

Àlékún (1)

نيل الأوطار (2/ 305).