Irẹ Ọlọhun dajudaju emi wa iṣọra pẹlu Rẹ kuro nibi iya saare, ati nibi iya ina, ati nibi fitina iṣẹmi ati iku, ati nibi fitina al-Masiihu ad-Dajjāl
Lati ọdọ Abu Hurayra - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe:
Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - jẹ ẹni ti maa n ṣe adua ti o si maa n sọ pe: «Irẹ Ọlọhun dajudaju emi wa iṣọra pẹlu Rẹ kuro nibi iya saare, ati nibi iya ina, ati nibi fitina iṣẹmi ati iku, ati nibi fitina al-Masiihu ad-Dajjāl». Nibi ti gbolohun ti Muslim: «Ti ẹnikẹni ninu yin ba ti pari ataaya igbẹyin, ki o yaa wa iṣọra pẹlu Ọlọhun kuro nibi awọn nkan mẹẹrin: Nibi iya jahannamọ, ati nibi iya saare, ati nini fitina iṣẹmi ati iku, ati nibi aburu al-Masiihu ad-Dajjāl».
كَانَ رَسُولُ اللَّهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ يَدْعُو وَيَقُولُ: «اللَّهُمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ مِنْ عَذَابِ القَبْرِ، وَمِنْ عَذَابِ النَّارِ، وَمِنْ فِتْنَةِ المَحْيَا وَالمَمَاتِ، وَمِنْ فِتْنَةِ المَسِيحِ الدَّجَّالِ». وفِي لَفْظٍ لِمُسْلِمٍ: «إِذَا فَرَغَ أَحَدُكُمْ مِنَ التَّشَهُّدِ الْآخِرِ، فَلْيَتَعَوَّذْ بِاللهِ مِنْ أَرْبَعٍ: مِنْ عَذَابِ جَهَنَّمَ، وَمِنْ عَذَابِ الْقَبْرِ، وَمِنْ فِتْنَةِ الْمَحْيَا وَالْمَمَاتِ، وَمِنْ شَرِّ الْمَسِيحِ الدَّجَّالِ».
Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - jẹ ẹni ti maa n wa iṣọra pẹlu Ọlọhun kuro nibi nkan mẹẹrin, lẹyin ataaya igbẹyin ati siwaju salamọ ninu irun, o si tun pa wa laṣẹ ki a maa wa iṣọra pẹlu Ọlọhun kuro nibẹ, Ikinni: Nibi iya saare. Ẹẹkeji: Nibi iya ina ati pe ìyẹn ni ọjọ igbedide. Ẹẹkẹta: Nibi fitina iṣẹmi bi awọn adun aye ti o jẹ eewọ ati awọn iruju ti maa n sọni nu, ati nibi fitina iku, ìyẹn ni àsìkò pipọka iku, bii yiyẹ kuro ninu Isilaamu tabi Sunnah, tabi fitina saare gẹgẹ bii ibeere awọn malaika mejeeji. Ẹẹkẹrin: Fitina al-Masiihu ad-Dajjāl eleyii ti yio jade ni igbẹyin aye, Ọlọhun yio fi i dan awọn ẹru Rẹ wo; o wa darukọ rẹ lọ́tọ̀ latari titobi fitina rẹ ati isọninu rẹ.
...:
Iwa iṣọra yii ninu awọn adua ti o pataki ti o si kun fọfọ ni, latari pe o ko iwa iṣọra kuro nibi awọn aburu aye ati alukiyaamọ sinu.
Ririnlẹ iya saare ati pe dajudaju ododo ni i.
Ewu awọn fitina ati pataki wiwa iranlọwọ pẹlu Ọlọhun ati ṣiṣe adua fun lila kuro ninu rẹ (fitina).
Fifi jijade dajjāl ati titobi fitina rẹ rinlẹ.
Ṣiṣe adua yii ni sunnah lẹyin ataaya igbẹyin.
Ṣiṣe adua ṣiṣe ni sunnah lẹyin iṣẹ oloore.
Tira Sọhiihu ti Bukhaariy (2/ 99) (1377).
Tira Sọhiihu ti Muslim (1/ 412) (588).
Tira Sọhiihu ti Bukhaariy (2/ 99) (1377).
Tira Sọhiihu ti Muslim (1/ 412) (588).
Àlékún (12)
الإلمام بشرح عمدة الأحكام.
لإسماعيل الأنصاري (1/ 172).
تيسير العلام شرح عمدة الأحكام.
للبسام (ص212).
خلاصة الكلام شرح عمدة الأحكام.
لفيصل آل مبارك (ص96).
الإلمام بشرح عمدة الأحكام.
لإسماعيل الأنصاري (1/ 172).
تيسير العلام شرح عمدة الأحكام.
للبسام (ص212).
خلاصة الكلام شرح عمدة الأحكام.
لفيصل آل مبارك (ص96).
A tọ́ka sí nínú àwọn ìwé
15 Àwọn Ìwé- Eleyii ni akọsilẹ soki kan nipa ẹsin Isilaamu gẹgẹ bi o ṣe wa ninu Alikuraani alapọnle pẹlu Sunnah Anọbi"Irẹ Ọlọhun, mo n sádi Ọ kúrò níbi ojo"
- حصن المسلم من أذكار الكتاب والسنةحصن المسلمIre Oluwa dajudaju emi wa iso pelu Re kuro nibi iya saare ati kuro nibi iya jahanama ati kuro nibi fitina isemi aiye ati fitina ti iku ati kuro nibi aburu fitina Masiihud-Dajjaal
- حصن المسلم من أذكار الكتاب والسنةحصن المسلماللَّهُــمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ مِنْ عَذَابِ القَبْرِ، وَمِنْ عَذَابِ جَهَنَّمَ، وَمِنْ فِتْنَةِ المَحْيَا وَالمَمَاتِ، وَمِنْ شَرِّ فِتْنَةِ المَسِيحِ الدَّجَّال
- Bí Anabi - kí ikẹ àti ọla Ọlọ́hun máa bá a - ṣe n kirun.كَيفِيَّةُ صَلَاةِ النَّبِيِّ ﷺ Irẹ Oluwa dajudaju emi wa isọ pẹlu Re kuro nibi iya jahanama, ati kuro nibi iya saare, ati kuro nibi fitina( idamu) isemi aiye ati fitina( wahala ) ti iku, ati kuro nibi aburu fitina ( idamu) Masiihud-Dajjaal[14].
- Nnkan ti ààyè o gba awọn ọmọde musulumi lati ma mọ ọn”"«Allāhummọ innī a‘ūdhu biKa minal jubni...»."
- Nnkan ti kò yẹ kí Musulumi ma mọ ọn nípa rẹ̀Ire Oluwa dajudaju emi wa isọ pelu Re kuro nibi iya jahanama, ati kuro nibi iya saare, ati kuro nibi fitina isemi aiye ati fitina ti iku, ati kuro nibi fitina Masiihud-Dajjaal[30].
Àlékún (9)
- الحقيقة المُبْهِرَة في العلاقة بين الإسلام والإنسان(اللهم إني أعوذ بك من جار السوء ..)[55].
- الخطب المنبريةموسوعة الخطب المنبرية (القسم الثالث)«إِذَا تَشَهَّدَ أَحَدُكُمْ فَلْيَسْتَعِذْ بِاللهِ مِنْ أَرْبَعٍ، يَقُولُ: اللَّهُمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ مِنْ عَذَابِ جَهَنَّمَ، وَمِنْ عَذَابِ القَبْرِ، وَمِنْ فِتْنَةِ الْمَحْيَا وَالْمَمَاتِ، وَمِنْ شَرِّ فِتْنَةِ المَسِيحِ الدَّجَّالِ»
- تطبيق القرآن والأذكارأذكار الصلاة((اللَّهُــمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ مِنْ عَذَابِ الْقَبْرِ، وَمِنْ عَذَابِ جَهَنَّمَ، وَمِنْ فِتْنَةِ الْمَحْيَا وَالْمَمَاتِ، وَمِنْ شَرِّ فِتْنَةِ الْمَسِيحِ الدَّجَّالِ))[79].
- رسالة في الأذكار1«إِذَا فَرَغَ أَحَدُكُمْ مِنَ التَّشَهُّدِ الْآخِرِ فَلْيَتَعَوَّذْ بِاللهِ مِنْ أَرْبَعٍ: مِنْ عَذَابِ جَهَنَّمَ، وَمِنْ عَذَابِ الْقَبْرِ، وَمِنْ فِتْنَةِ المَحْيَا وَالمَمَاتِ، وَمِنْ شَرِّ المَسِيحِ الدَّجَّالِ».
- رسالة موجزة عن الإسلام كما جاء في القرآن الكريم والسنة النبوية (مشتملة على الأدلة)رِسَالَةٌُ مُوجَزَةٌُ عَنِ الْإِسْلَامِ كَمَا جَاءَ فِي الْقُرْآنِ الْكَرِيمِ وَالسَّنَةِ النَّبَوِيَّة-مشتملة على الأدلة -للحرمين-«اللَّهُمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ مِنَ الجُبْنِ» [52].
- رياض الصالحينرياض الصالحين مع فوائد وهدايات - 7«إذَا تشَهَّدَ أحَدُكُم فَلْيَسْتَعذْ بالله من أرْبعٍ، يقولُ: اللهم إنِّي أعُوذُ بك مِن عذابِ جَهَنَّمَ، ومِن عذابِ القَبرِ، ومِن فتنةِ المَحْيَا والمَمَاتِ، ومِن شرِّ فتنةِ المسيحِ الدَّجَّالِ».
- صلاتنا الخاشعة"اللَّهُمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ مِنْ عَذَابِ جَهَنَّمَ، وَمِنْ عَذَابِ الْقَبْرِ، وَمِنْ فِتْنَةِ الْمَحْيَا وَالْمَمَاتِ، وَمِنْ شَرِّ فِتْنَةِ الْمَسِيحِ الدَّجَّالِ"([34]).
- مجموعة زاد التربية الإسلامية (2)1«إِذَا فَرَغَ أَحَدُكُمْ مِنْ التَّشَهُّدِ الْآخِرِ فَلْيَتَعَوَّذْ بِاﷲ مِنْ أَرْبَعٍ: مِنْ عَذَابِ جَهَنَّمَ، وَمِنْ عَذَابِ الْقَبْرِ، وَمِنْ فِتْنَةِ الْمَحْيَا وَالْمَمَاتِ، وَمِنْ شَرِّ الْمَسِيحِ الدَّجَّالِ».
- مشروع المنهج التعليميمادة الفقه مستوى 1«اللهُمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ مِنْ عَذَابِ جَهَنَّمَ، وَمِنْ عَذَابِ الْقَبْرِ، وَمِنْ فِتْنَةِ الْمَحْيَا وَالْمَمَاتِ، وَمِنْ شَرِّ فِتْنَةِ الْمَسِيحِ الدَّجَّالِ»