Skip to content
Al-Fatiha /

Ẹsẹ 1

1 : 1

Ẹsẹ 1 of Al-Fatiha (1 : 1). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

Al-Fatiha Àwọn Ẹsẹ 7
Súrà · Al-Fatiha
Yorùbá · Mikail
1 : 1

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

Ní orúkọ Allāhu, Àjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run.

Explanation & meanings · 1
  1. Sūratun Mọkkiyyah túmọ̀ sí sūrah tí ó sọ̀kalẹ̀ ṣíwájú Hijrah. Bákan náà, sūratun Mọdaniyyah túmọ̀ sí sūrah tí ó sọ̀kalẹ̀ lẹ́yìn Hijrah.