Skip to content
Awọn ipilẹ mẹta ati awọn ẹri rẹ

Awọn ipilẹ mẹta ati awọn ẹri rẹ

Iwe yii ṣe alaye awọn nnkan ipilẹ ti kíkọ́ wọn jẹ dandan fun musulumi: mímọ Ọlọhun, mímọ ẹsin Isilaamu, ati mímọ Anabi Muhammad (kí ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a), o si ṣe alaye pataki awọn ìpìlẹ wọnyi nibi gbigbe ìgbàgbọ́ ro ati ṣíṣe iṣẹ rere pẹlu gbigbarale awọn ẹri lati inu Alikuraani ati Hadiisi.

Èdè: lang_yo
Ẹni tí ó pèsè: Sheikh Muhammad At-Tamimi - kí Ọlọhun ba wa kẹ ẹ - ni o kọ
Ẹ̀yà: 2.0

These files are generated automatically from the book's text; their layout may differ from the printed edition.

0%
Font size