Skip to content

Parí hadīth: «Innamal a‘mālu bin niyyaat...», ki o si tun sọ díẹ̀ nínú awọn anfaani rẹ?

الباب / الفصل
قسم الحديث

السؤال

س1: أكمل حديث: «إنما الأعمال بالنيات ...»، واذكر بعض فوائده.

Ibeere 1: Parí hadīth: «Innamal a‘mālu bin niyyaat...», ki o si tun sọ díẹ̀ nínú awọn anfaani rẹ?

الجواب

ج:عن أمير المؤمنين أبي حفص عمر بن الخطاب رَضِيَ اللَّهُ تَعَالَى عَنْهُ قال: سمعت رسول الله صَلَّى اللهُ تَعَالَى عَلَيْهِ وعَلَى آَلِهِ وَسَلَّمَ يقول:

«إنما الأعمال بالنيات، وإنما لكل امرئ ما نوى، فمن كانت هجرته إلى الله ورسوله؛ فهجرته إلى الله ورسوله، ومن كانت هجرته لدنيا يصيبها، أو امرأة ينكحها؛ فهجرته إلى ما هاجر إليه»

رواه البخاري ومسلم.

فوائد من الحديث:

  1. كل عمل لا بد له من نية، من صلاة، وصوم، وحج، وغيرها من الأعمال.
  2. لا بد من الإخلاص في النية لله تَعَالَى.

Idahun- Lati ọdọ alaṣẹ awọn olugbagbọ ododo tii ṣe baba Hafs, Umar ọmọ khatāb - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe: Mo gbọ ti ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- n sọ pe:

«Dajudaju gbogbo iṣẹ n bẹ pẹlu aniyan, ati pe gbogbo nnkan ti ọmọniyan kọọkan ba gbero ni yio maa jẹ tiẹ, nitori naa ẹniti o ba ṣe hijirah tiẹ̀ nítorí ti Ọlọhun ati Ojiṣẹ Rẹ; yio gba ẹsan hijira rẹ nitori ti Ọlọhun ati Ojiṣẹ Rẹ, ẹni ti o ba si ṣe hijirah tiẹ̀ nitori aye tabi nitori obinrin ti o fẹẹ fẹ; ẹsan hijirah rẹ o maa bẹ lori nnkan ti o tori rẹ ṣe hijirah».

"Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa. "

Awọn anfaani inu Hadīth:

  1. Ko si ibuyẹ fun gbogbo iṣẹ nibi aniyan, bii Irun, ati Aawẹ, ati Hajj, ati eyiti o yatọ si i ninu awọn iṣẹ.

"2- Èèyàn gbọdọ̀ ni imọkanga nibi aniyan fun Ọlọhun."