Pari hadīth «Man ’ahdatha fī amrinā hādhā ...», ki o si tun darukọ awọn anfaani rẹ?"
- الباب / الفصل
- قسم الحديث
السؤال
س2: أكمل حديث «من أحدث في أمرنا هذا ...»، واذكر بعض فوائده.
"Ibeere 2: Pari hadīth «Man ’ahdatha fī amrinā hādhā ...», ki o si tun darukọ awọn anfaani rẹ?"
الجواب
ج:عن أم المؤمنين أم عبد الله عائشة رَضِيَ اللَّهُ عَنْهَا قالت: قال رسول الله ﷺ:
«من أحدث في أمرنا هذا ما ليس منه، فهو ردٌّ»
رواه البخاري ومسلم.
فوائد من الحديث:
- النهي عن الابتداع في الدين.
- وأن الأعمال المحدثة مردودة غير مقبولة.
"Idahun- Lati ọdọ iya gbogbo Mu’mini Umu Abdullāhi ‘Āishah ki Ọlọhun yọnu si i, o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- sọ pe:"
"«Ẹniti o ba da adadaalẹ ni inu alamọri yii ti ko si ninu rẹ, yio jẹ adapada fun un»"
"Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa. "
Awọn anfaani inu Hadīth:
"1- kikọ kuro nibi adadaalẹ ninu ẹsin"
"2- Ati pe dajudaju gbogbo iṣẹ ti o jẹ adadaalẹ nkan ti wọn o da pada ni ti ko nii jẹ atewọgba"