Skip to content
ما لا يسع أطفال المسلمين جهله

ما لا يسع أطفال المسلمين جهله

Oun ni oju-ọna kan to rọrun to pe nipa adisọkan, ati imọ agbọye ẹsin, ati itan, ati awọn ẹkọ, ati alaye ọrọ Ọlọhun, ati hadiisi, ati awọn iwa, ati awọn iranti, ti o dáa fun awọn ọmọde ati fun gbogbo ọjọ-ori, ati fun awọn ti wọn ṣẹṣẹ gba isilaamu, ti wọn o si maa lo o ni awọn ile ati ààyè itọju ati awọn ile-ẹkọ, ati fun iha, ati alaye, ti mo si to o ni ìbámu si awọn ẹka imọ, ti mo si ṣe e lori oju-ọna ibeere ati idahun; nitori pe ìyẹn ni nnkan ti o maa mu ọpọlọ mu berebere, ti o si maa n mu iha fidi mulẹ daadaa, ti olutọju o ṣe ẹsa ninu ẹ eyi ti o ba ba ọjọ-ori wọn mu.

0%
Font size