“Dajudaju adehun ti o wa laaarin wa ati laaarin wọn ni irun, ẹni ti o ba gbe e ju silẹ, dajudaju o ti ṣe aigbagbọ”.
- موضوعات الحديث
- الصلاةترك الصلاةالتوحيد وحمايتهالكفر وأنواعه
Lati ọdọ Buraida- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pé:
“Dajudaju adehun ti o wa laaarin wa ati laaarin wọn ni irun, ẹni ti o ba gbe e ju silẹ, dajudaju o ti ṣe aigbagbọ”.
«إِنَّ الْعَهْدَ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ».
Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣàlàyé pe dajudaju adehun ati majẹmu ti o wa laaarin awọn Musulumi ati laaarin awọn ti wọn yatọ si wọn ninu awọn alaigbagbọ ati awọn ṣọbẹ-selu ni irun kiki, ẹni ti o ba gbe e ju silẹ, dajudaju o ti ṣe aigbagbọ.
...:
Titobi ipo irun, ati pe oun ni ipinya ti o wa laaarin olugbagbọ ati alaigbagbọ.
Fifi awọn idajọ Isilaamu rinlẹ pẹlu nnkan ti o ba han ninu isẹsi awọn eniyan yatọ si eyi ti o pamọ.
Tira Sunanu ti An-Nasaaiy (1/ 231) (463).
Tira Sunanu ti Tirmidhiy (4/ 365) (2621).
Tira Sunanu ti Ọmọ Maajah (2/ 181) (1079).
Tira Musnad ti Ahmad (38/ 20) (22937).
Àlékún (2)
فيض القدير (4/ 395).
ذخيرة العقبى في شرح المجتبى (6/ 192) (6/ 193).
A tọ́ka sí nínú àwọn ìwé
14 Àwọn Ìwé- Nnkan ti ààyè o gba awọn ọmọde musulumi lati ma mọ ọn”«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»[33].
- Nnkan ti kò yẹ kí Musulumi ma mọ ọn nípa rẹ̀«Adehun ti n bẹ laarin wa ati laaarin wọn ni Irun, ẹnití o ba gbe e ju silẹ ti di keferi ( alaigbagbọ) » [15].
Àlékún (12)
- الصلاة التي علمها النبي ﷺ الصحابة رضي الله عنهمالصلاة التي علمها النبي ﷺ الصحابة رضي الله عنهم«إِنَّ الْعَهْدَ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلاَةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»[10].
- الصلاة التي علمها النبي ﷺ الصحابة رضي الله عنهم«إِنَّ الْعَهْدَ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»[10].
- الصيام ومجموعة أسئلة في أحكامه«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»[20]،
- رياض الصالحينرياض الصالحين مع فوائد وهدايات - 5«العهدُ الذي بينَنَا وبَيْنَهُمُ الصَّلاةُ، فَمَنْ ترَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ».
- قاموس الكبائر موسوعة الكبائر - المجموعة الأولى«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ» [59].
- قاموس الكبائر«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ» [59].
- مجموعة زاد التربية الإسلامية (1)، والسيرة النبوبة (1)، والعقيدة (1)، والفقه (1)مجموعة زاد الفقه (1)«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»
- مشروع المنهج التعليميمادة الفقه مستوى 1«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»
- مشروع المنهج التعليميمادة الفقه مستوى 1«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ ........»
- مشروع منهاج زادكزادك 1 طالب«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»
- من الأحكام الفقهية في الطهارة والصلاة والجنائز«الْعَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ: الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»[82].
- نبراس طالب (1)1«العَهْدُ الَّذِي بَيْنَنَا وَبَيْنَهُمُ الصَّلَاةُ، فَمَنْ تَرَكَهَا فَقَدْ كَفَرَ»