Skip to content

Obinrin kan ja awẹ ninu Ramadan fun ọjọ meje ti o si jẹ ẹni ti ẹjẹ ìbímọ n da lara rẹ, ko si san an pada titi ti Ramadan keji fi wọle ba a, o tun ja awẹ ọjọ méje mìíràn ninu Ramadan keji ti o jẹ ẹni ti o n fun ọmọ ni ọyan, ti ko san an pada pẹlu awijare aisan kan ti o mu u, ki ni nnkan ti o jẹ dandan fun un ki Ramadan kẹta si ti fẹ wọle? Ẹ ṣe wa ni anfaani, Ọlọhun A san yin ni ẹsan.

السؤال

Ibeere akọkọ:

س19: امرأةٌ أفطرت في رمضان سبعة أيامٍ وهي نفساء، ولم تقض حتى أتاها رمضان الثاني، وطافها من رمضان الثاني سبعة أيامٍ وهي مرضعٌ، ولم تقض؛ بحجّة مرضٍ عندها، فماذا عليها وقد أوشك دخول رمضان الثالث؟ أفيدونا أثابكم الله.

الجواب

Idahun akọkọ:

Ti obinrin yii ba ri bi o ṣe sọ nipa ara rẹ̀- pe oun wa ninu aisan, ti ko si ni agbara ati san an pada- dajudaju yoo gba a pada ni igba ti o ba ti ni ikapa; nitori pe o jẹ ẹni ti a fun ni awijare, koda ki Ramadan keji wọle

Ṣugbọn ti o ba ṣe pe ko si awijare fun un, bi ko ṣe pe o kan n wa àwíjàre lasan ni ti ko si ni àkàkún, ko lẹtọọ fun un lati lọ sisan awẹ pada lara di Ramadan keji

" 'Aaisha- ki Ọlọhun yọnu si i- sọ pe: Mo maa n jẹ awẹ, ti mi ko nii ni ikapa lati da a pada afi ninu Sha'ban

"Lori eyi, o jẹ dandan fun obinrin naa lati kiyesi ara rẹ, ti ko ba si awijare fun un o ti jẹ ẹlẹṣẹ, o jẹ dandan fun un lati ronupiwada lọ si ọdọ Ọlọhun, ki o tete lọ san nnkan ti o n bẹ lọrun rẹ pada ninu awẹ, ṣùgbọ́n ti o ba ni awijare ko si ẹṣẹ fun un, ko da ki o lọ ọ lara fun ọdun kan tabi ọdun meji

ﺟ19: إذا كانت هذه المرأة كما ذكرت عن نفسها -أنها في مرضٍ، ولا تستطيع القضاء- فإنها متى استطاعت صامته؛ لأنها معذورةٌ، حتى ولو جاء رمضان الثاني.

أما إذا كان لا عذر لها، وإنما تتعلل وتتهاون، فإنه لا يجوز لها أن تؤخّر قضاء رمضان إلى رمضان الثاني، قالت عائشة رضي الله عنها:

«كَانَ يَكُونُ عَلَيَّ الصَّوْمُ، فَمَا أَسْتَطِيعُ أَنْ أَقْضِيَهُ إِلَّا فِي شَعْبَانَ» [1].

[4] البخاري، كتاب الصوم، باب متى يقضي قضاء رمضان (1950)، ومسلم، كتاب الصيام، باب في جواز تأخير قضاء رمضان (151) (1147).

وعلى هذا، فعلى هذه المرأة أن تنظر في نفسها، إذا كان لا عذر لها فهي آثمةٌ، وعليها أن تتوب إلى الله، وأن تبادر بقضاء ما في ذمتها من الصّيام، وإن كانت معذورةً فلا حرج عليها، ولو تأخرت سنةً أو سنتين.