Apakan awọn obinrin, Ramadan keji maa wọle ba wọn ti wọn ko si tii gba awọn ọjọ kan ninu Ramadan ti o ṣáájú, ki ni nnkan ti o jẹ dandan fun wọn?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Apakan awọn obinrin, Ramadan keji maa wọle ba wọn ti wọn ko si tii gba awọn ọjọ kan ninu Ramadan ti o ṣáájú, ki ni nnkan ti o jẹ dandan fun wọn?
س20: بعض النّساء يدخل عليهن رمضان الثاني وهن لم يصمن أيامًا من رمضان السابق، فما الواجب عليهن؟
الجواب
Idahun akọkọ:
" Nnkan ti o jẹ dandan fun wọn ni: Ironupiwada lọ si ọdọ Ọlọhun kuro nibi iṣẹ yii; nitori pe ko lẹtọọ fun ẹni ti o jẹ Ramadan lati lọ ọ lara di Ramadan keji laisi àwíjàre kankan; fun ọrọ 'Aaisha- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pe: Mo maa n jẹ awẹ Ramadan, ti mi o si nii ni ikapa lati da a pada afi ninu Sha'ban.
Eyi n tọka si pe lilọ ọ lara ko rọrun di ẹyin Ramadan keji, dandan ni fun un láti ronupiwada si ọdọ Ọlọhun- Alagbara ti O gbọnngbọn- nibi nǹkan ti o ṣe, ki o si san awọn ti o gbe ju silẹ pada lẹyin Ramadan keji
جـ20: الواجب عليهن: التوبة إلى الله من هذا العمل؛ لأنه لا يجوز لـمن عليه قضاء رمضان أن يؤخّره إلى رمضان الثاني بلا عذرٍ؛ لقول عائشة رضي الله عنها:
«كَانَ يَكُونُ عَلَيَّ الصَّوْمُ مِنْ رَمَضَانَ، فَمَا أَسْتَطِيعُ أَنْ أَقْضِيَهُ إِلَّا فِي شَعْبَانَ».
وهذا يدلّ على أنه لا يمكن تأخيره إلى ما بعد رمضان الثاني، فعليها أن تتوب إلى الله عز وجل مما صنعت، وأن تقضي الأيام التي تركتها بعد رمضان الثّاني.