Skip to content

Njẹ pipaarọ awọn aṣọ rẹ jẹ dandan fun ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu lẹyin mimọ, pẹlu nini imọ pe dajudaju ẹjẹ ko da si i tabi ẹgbin?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Njẹ pipaarọ awọn aṣọ rẹ jẹ dandan fun ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu lẹyin mimọ, pẹlu nini imọ pe dajudaju ẹjẹ ko da si i tabi ẹgbin?

س18: هل يلزم الحائض تغيير ملابسها بعد طهرها، مع العلم أنه لم يصبها دمٌ ولا نجاسةٌ؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Iyẹn ko jẹ dandan fun un; nitori pe nnkan oṣu ko lee ko ẹgbin ba ara, bi ko ṣe pe ẹjẹ nnkan oṣu maa n ko ẹgbin ba nnkan ti o ba kàn nikan ni, fun idi eyi, Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- paṣẹ fun awọn obinrin ti ẹjẹ nnkan oṣu ba da si aṣọ wọn lati fọ wọn, ki wọn si ki irun ninu awọn aṣọ wọn

ﺟ18: لا يلزمها ذلك؛ لأن الحيض لا ينجّس البدن، وإنما دم الحيض ينجّس ما لاقاه فقط، ولهذا أمر النبي ﷺ النّساء إذا أصاب ثيابهن دم حيضٍ أن يغسلنه، ويصلّين في ثيابهن.