Ti obinrin ba bẹ̀rẹ̀ nnkan oṣu ni aago kan ọsan fun apẹrẹ, ti ko si tii ki irun Zuhr, njẹ sisan irun yẹn pada jẹ dandan fun un lẹyin imọra bi?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ti obinrin ba bẹ̀rẹ̀ nnkan oṣu ni aago kan ọsan fun apẹrẹ, ti ko si tii ki irun Zuhr, njẹ sisan irun yẹn pada jẹ dandan fun un lẹyin imọra bi?
س21: إذا حاضت المرأة الساعة الواحدة ظهرًا مثلًا، وهي لم تصلّ بعد صلاة الظّهر، فهل يلزمها قضاء تلك الصلاة بعد الطّهر؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Iyapa ẹnu wa nibi eyi laaarin awọn onimimọ, o n bẹ ninu wọn ẹni ti o sọ pe: Ko jẹ dandan fun un lati san irun yii pada; nitori pe ko ṣe àseètó, ko si da ẹṣẹ; torí pé o lẹtọọ fun un lati lọ irun lara di ipari asiko rẹ
O n bẹ ninu wọn ẹni ti o sọ pe: Sisan an pada jẹ dandan fun un, o n túmọ̀ si: Sisan irun yẹn pada; fun akotan ọrọ rẹ- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-:
“Ẹni ti o ba ba ra'kah kan ninu irun ti ba irun”
Ohun ti o fi ni lọ́kàn balẹ̀ ni: Ki o san an pada; nitori pe o jẹ irun ẹyọkan, ti ko si wahala nibi sisan an pada
ﺟ21: في هذا خلافٌ بين العلماء، فمنهم من قال: إنه لا يلزمها أن تقضي هذه الصلاة؛ لأنها لم تفرط، ولم تأثم؛ حيث إنه يجوز لها أن تؤخّر الصلاة إلى آخر وقتها.
ومنهم من قال: إنه يلزمها القضاء، أي: قضاء تلك الصلاة؛ لعموم قوله ﷺ:
«مَنْ أَدْرَكَ رَكْعَةً مِنَ الصَّلَاةِ فَقَدْ أَدْرَكَ الصَّلَاةَ» [1].
[5] تقدم تخريجه.
والاحتياط لها: أن تقضيها؛ لأنها صلاةٌ واحدةٌ، لا مشقة في قضائها.