Skip to content

Pari hadiisi “Ẹ gbọ o, baaṣi ẹran kan n bẹ ninu ara…”, ki o si darukọ awọn apa kan anfaani rẹ?

الباب / الفصل
قسم الحديث

السؤال

س10: أكمل حديث «ألا إن في الجسد مضغة...»، واذكر بعض فوائده.

Ibeere 10: Pari hadiisi “Ẹ gbọ o, baaṣi ẹran kan n bẹ ninu ara…”, ki o si darukọ awọn apa kan anfaani rẹ?

الجواب

ج:عن النعمان بن بشير رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُما قال: سمعت رسول الله صلى الله عليه وسلم يقول:

«ألا وإن في الجسد مضغة إذا صلحت صلح الجسد كله، وإذا فسدت فسد الجسد كله، ألا وهي القلب»

رواه البخاري ومسلم.

بعض فوائد الحديث:

  1. صلاح القلب فيه صلاح الظاهر والباطن.
  2. الاهتمام بصلاح القلب لأن به صلاح الإنسان.

Idahun: Nu'maan ọmọ Basheer (ki Ọlọhun yọnu si i) sọ pe: Mo gbọ ti ojiṣẹ Ọlọhun (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) n sọ pe:

“Ẹ gbọ o, baaṣi ẹran kan n bẹ ninu ara, ti o ba dara, gbogbo ara ni yoo dara, ti o ba si bajẹ, gbogbo ara ni yoo bajẹ, ẹ gbọ o, oun naa ni ọkan”.

"Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa. "

Anfaani ti a maa ṣe lara Hadiisi naa ni pe

  1. Didara ọkan yoo jẹ ki gban-angba ati kọkọ o dara.
  2. Nini akolekan didara ọkan, nitori pe ibẹ ni didara ọmọniyan wa.