Skip to content

Parí hadiisi yii: “Ẹni ti igbẹyin ọrọ rẹ nile aye ba jẹ: Laa ilaaha ilaLlah...”, ki o si darukọ awọn apa kan anfaani rẹ?

الباب / الفصل
قسم الحديث

السؤال

س11: أكمل حديث: «من كان آخر كلامه -من الدنيا- لا إله إلا الله..»، واذكر بعض فوائده.

Ibeere 11: Parí hadiisi yii: “Ẹni ti igbẹyin ọrọ rẹ nile aye ba jẹ: Laa ilaaha ilaLlah...”, ki o si darukọ awọn apa kan anfaani rẹ?

الجواب

ج:عن معاذ بن جبل رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ قال: قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:

«من كان آخر كلامه: لا إله إلا الله؛ دخل الجنة»

رواه أبو داود.

بعض فوائد الحديث:

  1. فضل لا إله إلا الله، وأن العبد يدخل بها الجنة.
  2. وفضل من كان آخر كلامه من الدنيا لا إله إلا الله.

Idahun: Lati ọdọ Muaadh ọmọ Jabal (ki Ọlọhun yọnu si i) o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) sọ pe:

“Ẹni tí igbẹyin ọrọ rẹ nile aye ba jẹ: Laa ilaaha illaal Looh; yoo wọ alijanna”.

Abu Daud ni o gba a wa.

Anfaani ti a maa ṣe lara Hadiisi naa ni pe

  1. Ọla ti n bẹ fun "Laa ilaaha illaLlaah" ati pe ẹrusin yoo wọ alujanna pẹlu rẹ.
  2. Ọla ti n bẹ fun ẹni tí igbẹyin ọrọ rẹ ni ile aye yii ba jẹ "Laa ilaaha illaLlaah"