Skip to content

Pari Hadiisi “Kii ṣe olugbagbọ ododo ni ẹni tí maa n saaba bu ẹnu atẹ lu àwọn èèyàn, tabi ẹni ti máa n saaba sẹbi le àwọn eeyan…”, ati diẹ ninu awọn anfaani rẹ?

الباب / الفصل
قسم الحديث

السؤال

س12: أكمل حديث «ليس المؤمن بالطعان، ولا اللعان ...»، وبعض فوائده.

Ibeere 12: Pari Hadiisi “Kii ṣe olugbagbọ ododo ni ẹni tí maa n saaba bu ẹnu atẹ lu àwọn èèyàn, tabi ẹni ti máa n saaba sẹbi le àwọn eeyan…”, ati diẹ ninu awọn anfaani rẹ?

الجواب

ج:عن عبد الله بن مسعود رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ قال: قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:

«ليس المؤمن بالطعان، ولا اللعان، ولا الفاحش، ولا البذيء»

رواه الترمذي.

من فوائد الحديث:

  • النهي عن كل كلام باطل وقبيح.
  • أن ذلك صفة المؤمن في لسانه.

Idahun: Lati ọdọ Abdullah ọmọ Mas'uud (ki Ọlọhun yọnu si i) o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) sọ pe:

"Mu'mini o ki n ṣe ẹni tí maa n yọ aleebu ara eeyan, ko si ki n ṣe ẹni tí maa n ṣepe, ko si ki n ṣe oni ibajẹ, ko si ki n ṣe ẹlẹnu jijo (ti ko si ọrọ ti ko le sọ)

Tirmidhiy ni o gba a wa

"Ninu awọn anfaani to wa ninu Hadiisi naa: "

"1-Kikọ kuro nibi gbogbo ọrọ ibajẹ ati ọrọ buruku. "

Dajudaju iyẹn jẹ iroyin olugbagbọ nibi ahọn rẹ. "