Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹsan-an: Parí Hadiisi: “Laa hawla wa laa quwwata illa bi-Llah…”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ? "

الباب / الفصل
قسم الحديث

السؤال

س9: أكمل حديث «لا حول ولا قوة إلا بالله ...»، واذكر بعض فوائده.

"Ibeere ẹlẹẹkẹsan-an: Parí Hadiisi: “Laa hawla wa laa quwwata illa bi-Llah…”, ki o si darukọ diẹ ninu awọn anfaani ẹ? "

الجواب

ج:عن أبي موسى رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ، قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:

«لا حول ولا قوة إلا بالله كنز من كنوز الجنة»

رواه البخاري ومسلم.

من فوائد الحديث:

  1. فضل هذه الكلمة، وأنها كنز من كنوز الجنة.
  2. تبرُّؤُ العبد من حوله وقوته، واعتماده على الله تَعَالَى وحده.

"Idahun- lati ọdọ Abu Musa-ki Ọlọhun yọnu si i- Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "

“Laa hawla wa laa quwwata illa bi-Llah jẹ pẹpẹ ọrọ kan ninu awọn pẹpẹ ọrọ alujanna”.

"Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa. "

"Ninu awọn anfaani to wa ninu Hadiisi naa: "

  1. Ọla ti n bẹ fun gbolohun yii, ati pe pẹpẹ ọrọ kan ni in ninu awọn pẹpẹ ọrọ alijanna.
  2. Yoo mu ẹrusin bọpa bọsẹ kuro nibi ìkápá ati agbara rẹ ati gbigbara le Ọlọhun- Ọba ti ola Rẹ ga- nikan ṣoṣo.