Skip to content

Mo ti ṣe hajj ni ọdún ti o kọjá, mo si pe gbogbo awọn iṣẹ hajj yatọ si tawaaful ifaadoh ati tawaafu idagbere, nigba ti o ṣe pe àwíjàre ti o ba sharia mu ni ko jẹ ki n le ṣe mejeeji, mo wa ṣeri pada si ile mi ni Mọdina lori pe ki n pada ni ọjọ mìíràn; lati lọ ṣe tawaaful ifaadoh ati ti idagbere, ṣùgbọ́n pẹ̀lú aimọkan mi nípa awọn alamọri ẹsin, mo bọ́ra kúrò nibi gbogbo nnkan, mo ṣe gbogbo nnkan ti wọn ṣe ni eewọ nínú áràmí, mo wa beere nipa ṣiṣẹri pada mi lati rọkirika ile Oluwa, wọn sọ fun mi pe: Ko tọ fun ẹ lati rọkirika ile Oluwa, o ti ba hajj jẹ, titun un ṣe si jẹ dandan fun ẹ ni ọdun ti o n bọ, pẹ̀lú didu maalu tabi abo rakunmi, njẹ eyi tọna? Njẹ ọ̀nà àbáyọ mii wa? Ki ni nnkan náà? Njẹ Hajj mi ti bajẹ? Njẹ dida pada rẹ jẹ dandan fun mi? Ẹ ṣe mi ni anfaani pẹlu nnkan ti maa ṣe, Ọlọhun a bukun yin

السؤال

Ibeere akọkọ:

Mo ti ṣe hajj ni ọdún ti o kọjá, mo si pe gbogbo awọn iṣẹ hajj yatọ si tawaaful ifaadoh ati tawaafu idagbere, nigba ti o ṣe pe àwíjàre ti o ba sharia mu ni ko jẹ ki n le ṣe mejeeji, mo wa ṣeri pada si ile mi ni Mọdina lori pe ki n pada ni ọjọ mìíràn; lati lọ ṣe tawaaful ifaadoh ati ti idagbere, ṣùgbọ́n pẹ̀lú aimọkan mi nípa awọn alamọri ẹsin, mo bọ́ra kúrò nibi gbogbo nnkan, mo ṣe gbogbo nnkan ti wọn ṣe ni eewọ nínú áràmí, mo wa beere nipa ṣiṣẹri pada mi lati rọkirika ile Oluwa, wọn sọ fun mi pe: Ko tọ fun ẹ lati rọkirika ile Oluwa, o ti ba hajj jẹ, titun un ṣe si jẹ dandan fun ẹ ni ọdun ti o n bọ, pẹ̀lú didu maalu tabi abo rakunmi, njẹ eyi tọna? Njẹ ọ̀nà àbáyọ mii wa? Ki ni nnkan náà? Njẹ Hajj mi ti bajẹ? Njẹ dida pada rẹ jẹ dandan fun mi? Ẹ ṣe mi ni anfaani pẹlu nnkan ti maa ṣe, Ọlọhun a bukun yin

س51: لقد قمت بأداء فريضة الحجّ العام الماضي، وأديت جميع شعائر الحجّ ما عدا طواف الإفاضة وطواف الوداع، حيث منعني منهما عذرٌ شرعيٌّ، فرجعت إلى بيتي في الـمدينة على أن أعود في يومٍ من الأيام؛ لأطوف طواف الإفاضة وطواف الوداع، وبجهلٍ منّي بأمور الدّين فقد تحللت من كلّ شيءٍ، وفعلت كل شيءٍ يحرم أثناء الإحرام، وسألت عن رجوعي لأطوف، فقيل لي: لا يصحّ لك أن تطوفي، فقد أفسدتّه، وعليك الإعادة -أي: إعادة الحجّ مرةً أخرى- في العام المقبل، مع ذبح بقرةٍ أو ناقةٍ، فهل هذا صحيحٌ؟ وهل هناك حلٌّ آخر؟ وما هو؟ وهل فسد حجّي؟ وهل عليّ إعادته؟ أفيدوني عمّا يجب فعله، بارك الله فيكم.

الجواب

Idahun akọkọ:

Eyi naa wa ninu awọn adanwo ti o n ṣẹlẹ ninu ṣíṣe alaye idajọ laini imọ, iwọ ti o wa ninu iṣesi yii, o jẹ dandan fun ẹ lati ṣeri pada si Makkah lati lọ ṣe tawaaful ifaadoh nikan.

Ṣugbọn nípa irọkirika ile Oluwa ti idagbere, ko jẹ dandan fun ẹ, ni iwọn igba ti o ba si jẹ ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu nigba ti o jáde kuro ni Makkah, iyẹn ri bẹ́ẹ̀ nitori pe ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu, irọkirika ile Oluwa ti idagbere ko jẹ dandan fun un

Fun hadisi Ibnu Abbas- ki Ọlọhun yọnu si wọn-: Wọn pa awọn eniyan láṣẹ lati jẹ ki igbẹyin iṣẹ́ hajj wọn jẹ irọkirika ile Oluwa, ṣùgbọ́n wọn ṣe e ni fifuyẹ fun ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu

Ninu ẹgbawa ti Abu Daud: Ki igbẹyin iṣẹ́ ti wọn a ṣe ni ilé Olúwa jẹ irọkirika ile naa.

Nitori pe Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nigba ti wọn fun un ni iro nipa pe Sofiyyah ṣe tawaaful ifaadoh, o sọ pe: “Ti o ba ri bẹ́ẹ̀, ki o yaa maa lọ”.

Eyi da lori pe irọkirika ile Oluwa ti idagbere ko nii jẹ dandan fun ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu.

Ṣugbọn irọkirika ile Oluwa ti ifaadọ, o jẹ dandan fun ẹ, nigba ti o ti wa bọra kuro nibi gbogbo nnkan ni ẹni ti o ṣe aimọkan pẹlu rẹ, dajudaju eyi ko ko inira ba ẹ; nitori pe alaimọkan ti o ṣe nnkankan ninu awọn eewọ gbigbe arami, ko si nǹkan kan fun un;

Fun ọrọ Ọba ti ọla Rẹ ga pe: {Olúwa wa, má ṣe mú wa tí a bá gbàgbéra tàbí (tí) a bá ṣàṣìṣe}[Surah Al-Baqarah: 286]

Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- sọ pe: “Mo ti ṣe e”.

Ati ọrọ Rẹ pe: {Kò sí ẹ̀ṣẹ̀ fun yín nípa ohun tí ẹ bá ṣàṣìṣe rẹ̀, ṣùgbọ́n (ẹ̀ṣẹ̀ wà níbi) ohun tí ọkàn yín mọ̀ọ́mọ̀ ṣe}[Surah Al-Ahzâb: 5]

Gbogbo nnkan eewọ ti Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- kọ wọn fun ẹni ti o gbe arami, ti o ba ṣe e ni ti aimọkan tabi ni ẹni ti o gbagbe, tabi ni ẹni ti wọn jẹnípá, ko si ẹṣẹ kankan fun un, ṣugbọn gbogbo igba ti awijare rẹ ba ti kúrò, o jẹ dandan fun un lati jáwọ́ kuro nibi nnkan eewọ naa.

ﺟ51: هذا أيضًا من البلاء الّذي يحصل من الفتوى بغير علمٍ، وأنت في هذه الحال يجب عليك أن ترجعي إلى مكة، وتطوفي طواف الإفاضة فقط.

أما طواف الوداع فليس عليك طواف وداعٍ ما دمت كنت حائضًا عند الخروج من مكة، وذلك لأن الحائض لا يلزمها طواف الوداع؛ لحديث ابن عباسٍ رضي الله عنهما:

«أُمِرَ النَّاسُ أَنْ يَكُونَ آخِرُ عَهْدِهِمْ بِالْبَيْتِ، إِلَّا أَنَّهُ خُفِّفَ عَنِ الْحَائِضِ» [1]،

وفي روايةٍ لأبي داود:

«أَنْ يَكُونَ آخِرُ عَهْدِهِمْ بِالْبَيْتِ الطَّوَافُ» [2].

ولأن النبي ﷺ لـمّا أخبر أنّ صفيّة طافت طواف الإفاضة قال:

«فَلْتَنْفِرْ إِذًا» [3]،

فدلّ هذا على أن طواف الوداع يسقط عن الحائض.

[19] أخرجه البخاري، كتاب الحج، باب طواف الوداع (1755)، ومسلم، كتاب الحج، باب وجوب طواف الوداع وسقوطه عن الحائض (380) (1328).

[20] أخرجه أبو داود، كتاب المناسك، باب الوداع (2002).

[21] أخرجه البخاري، كتاب الحيض، باب المرأة تحيض بعد الإفاضة (328)، ومسلم، كتاب الحج، الباب السابق (382) (1211).

أما طواف الإفاضة فلابد لك منه، ولـما كنت تحللت من كلّ شيءٍ جاهلةً فإن هذا لا يضرّك؛ لأن الجاهل الذي يفعل شيئًا من محظورات الإحرام لا شيء عليه؛ لقوله تعالى:

﴿...رَبَّنَا لَا تُؤَاخِذۡنَآ إِن نَّسِينَآ أَوۡ أَخۡطَأۡنَاۚ...﴾

[البقرة:286]،

قال الله تعالى:

«قَدْ فَعَلْتُ» [4]،

وقوله:

﴿...وَلَيۡسَ عَلَيۡكُمۡ جُنَاحٞ فِيمَآ أَخۡطَأۡتُم بِهِۦ وَلَٰكِن مَّا تَعَمَّدَتۡ قُلُوبُكُمۡۚ...﴾

[الأحزاب:5]،

فجميع الـمحظورات الّتي منعها الله تعالى على المحرم إذا فعلها جاهلًا أو ناسيًا أو مكرهًا فلا شيء عليه، لكن متى زال عذره وجب عليه أن يقلع عما تلبس به.

[22] أخرجه مسلم، كتاب الإيمان، باب بيان تجاوز الله تعالى عن حديث النفس (200) (126).