Obinrin ti o ẹjẹ ibimọ n da lara rẹ, ti ẹjẹ ibimọ rẹ ba bẹrẹ ni ọjọ kẹjọ ninu oṣu Dhul-Hijjah, ti o ti pari awọn origun Hajj yatọ si irọkirika ile Oluwa ati sisa safa ati mariwa, ṣùgbọ́n o ṣe akiyesi pe oun ti kọ́kọ́ mọ́ lẹyin ọjọ mẹwaa, njẹ yoo mọra, ti yoo wẹ, ti yoo si pe origun ti o ṣẹku ti o jẹ pe oun ni irọkirika ile Oluwa ti Hajj?
السؤال
Ibeere akọkọ:

س52: المرأة النّفساء إذا بدأ نفاسها يوم التروية، وأكملت أركان الحجّ عدا الطواف والسعي، إلا أنها لاحظت أنها طهرت مبدئيًّا بعد عشرة أيامٍ، فهل تتطهر، وتغتسل، وتؤدّي الرّكن الباقي الّذي هو طواف الحجّ؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Ko lẹtọọ fun un lati wẹ ati lati rọkirika ile Oluwa titi ti mimọ yoo fi da a loju, nnkan ti a n gbọye ninu ibeere naa nigba ti o sọ pe: “Kọ́kọ́” ni pe ko ri mimọ ni pipe, dandan si ni ki o ri mimọ ni pepe, igbakigba ti o ba mọ́ ni yoo wẹ, yoo si ṣe tawaafu ati safa ati mariwa naa.
Ti o ba sá sàfá àti máríwà ṣiwaju irọkirika ile Oluwa, ko burú; nitori pe Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- wọn bi i leere ni Hajj nipa ẹni ti o sa safa ati mariwa ṣiwaju ki o to rọkirika ile Oluwa, o sọ pe: “Kò burú”
ﺟ52: لا يجوز لها أن تغتسل وتطوف حتى تتيقن الطّهر، والّذي يفهم من السّؤال حين قالت: (مبدئيًّا) أنها لم تر الطّهر كاملًا، فلابد أن ترى الطّهر كاملًا، فمتى طهرت اغتسلت، وأدت الطواف والسعي.
وإن سعت قبل الطواف فلا حرج؛ لأن النبي ﷺ سئل في الحجّ عمن سعى قبل أن يطوف، فقال:
«لَا حَرَجَ» [1].
[23] رواه أبو داود، كتاب المناسك، باب فيمن قدم شيئًا قبل شيء في حجه (2015).