Ki ni idajọ Musulumi-binrin ti o ṣe nnkan oṣu ni awọn ọjọ Hajj rẹ, njẹ hajj yẹn to fun un?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ki ni idajọ Musulumi-binrin ti o ṣe nnkan oṣu ni awọn ọjọ Hajj rẹ, njẹ hajj yẹn to fun un?
س50: ما حكم المرأة المسلمة التي حاضت في أيام حجّها، أيجزئها ذلك الحج؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Eyi ko ṣee dahun si titi ti a fi maa mọ igba ti o ṣe nnkan oṣu? Iyẹn ri bẹ́ẹ̀ nitori pe awọn iṣẹ Hajj kan n bẹ ti nnkan oṣu ko lee ni ki èèyàn má ṣe wọn, àwọn iṣẹ́ kan naa si wa ti nǹkan oṣù ko nii jẹ ki a le ṣe wọn, gẹgẹ bii irọkirika ile Oluwa, ko rọrun lati rọkirika rẹ afi ki o jẹ ẹni ti o mọ, ṣùgbọ́n o rọrun lati ṣe àwọn iṣẹ́ hajj ti o yatọ si i pẹ̀lú nǹkan oṣù.
ﺟ50: هذا لا يمكن الإجابة عنه حتى يعرف متى حاضت؟ وذلك لأن بعض أفعال الحجّ لا يمنع الحيض منه، وبعضها يمنع منه، فالطواف لا يمكن أن تطوفه إلا وهي طاهرٌ، وما سواه من المناسك يمكن فعله مع الحيض.