Skip to content

Obinrin kan gbe arami Hajj lati ààyè kan ti a n pe ni “Sael” ni ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu, nigba ti o de Makkah, o lọ si Jeddah fun bukaata rẹ, o mọ ni Jeddah, o si wẹ, o si ya irun rẹ, lẹyin naa o ṣe Hajj rẹ ni aṣepe, njẹ Hajj rẹ ni alaafia? Njẹ nnkankan jẹ dandan fun un?

السؤال

Ibeere akọkọ:

س53: امرأةٌ أحرمت بالحجّ من السّيل وهي حائضٌ، ولـما وصلت إلى مكة ذهبت إلى جدة؛ لحاجةٍ لها، وطهرت في جدّة، واغتسلت، ومشطت شعرها، ثم أتمت حجها، فهل حجّها صحيحٌ؟ وهل يلزمها شيءٌ؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Hajj rẹ ni alaafia, nnkankan ko jẹ dandan fun un

ﺟ53: حجّها صحيحٌ، ولا شيء عليها.