Skip to content

Obìnrin kan ti ijanba ṣẹlẹ si i, ti o si wa ni ibẹrẹ oyún, ọmọ naa si jabọ lẹyin jíjáde ẹjẹ ti o pọ ga, njẹ o jẹ dandan fun un lati ja awẹ, tabi ki o tẹsiwaju pẹlu awẹ? Ti o ba ja awẹ, njẹ ẹṣẹ n bẹ fun un bi?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Obìnrin kan ti ijanba ṣẹlẹ si i, ti o si wa ni ibẹrẹ oyún, ọmọ naa si jabọ lẹyin jíjáde ẹjẹ ti o pọ ga, njẹ o jẹ dandan fun un lati ja awẹ, tabi ki o tẹsiwaju pẹlu awẹ? Ti o ba ja awẹ, njẹ ẹṣẹ n bẹ fun un bi?

س28: امرأةٌ أصيبت في حادثةٍ، وكانت في بداية الحمل، فأسقطت الجنين إثر نزيفٍ حادٍّ، فهل يجوز لها أن تفطر، أو تواصل الصّيام؟ وإذا أفطرت فهل عليها إثمٌ؟

الجواب

Idahun akọkọ:

A maa sọ pe: Dajudaju oloyun ko le ṣe nnkan oṣu, gẹgẹ bi Imam Ahmad ṣe sọ: Awọn obinrin maa n da oyún mọ pẹlu ki nnkan oṣu dúró. Ati pe nnkan oṣu- gẹgẹ bi awọn onimimọ ṣe sọ- Ọlọhun- ìbùkún ni fun Un ti ọla Rẹ ga- ṣẹda rẹ fun ọgbọn jijẹ oúnjẹ ọmọ ninu ikun iya rẹ, ti oyun ba ti bẹrẹ, ẹjẹ nnkan oṣu maa da

Ṣugbọn awọn obinrin kan maa n ṣe nnkan oṣu lọ lori iṣesi rẹ gẹgẹ bi o ṣe wa ṣiwaju oyun, idajọ eléyìí ni pe nǹkan oṣù rẹ ni alaafia; torí pé ẹjẹ nnkan oṣu rẹ n lọ, oyun naa ko lapa lara rẹ, nnkan oṣu yii maa kọ gbogbo nnkan ti nǹkan oṣù ẹni tí ko loyun maa n kọ, o si maa sọ ohun ti o ba maa n sọ di dandan di dandan, o si maa mu kuro ohun ti o ba maa n mu kúrò.

Ni akotan: Dajudaju ẹjẹ ti o n jade latara oloyun jẹ iran meji:

Iran kan jẹ ẹjẹ nnkan oṣu, oun ni eyi ti o tẹsiwaju pẹlu rẹ gẹgẹ bi o ṣe wa ṣiwaju oyun, itumọ iyẹn ni pe: Oyun ko lapa lara rẹ, yoo si jẹ ẹjẹ nnkan oṣu.

Iran keji: Ẹjẹ kan ti o ṣẹlẹ si oyun lojiji, ninu ki o jẹ pe pẹlu okunfa ijanba kan, tabi gbigbe nnkankan, tabi jijabọ lati ori nnkankan ati nnkan ti o jọ ọ, ẹjẹ rẹ ni eyi kii ṣe ẹjẹ nnkan oṣu, bi ko ṣe pe ẹjẹ iṣan ni

Lori eyi ko lee kọdi rẹ nibi irun, tabi awẹ, bi ko ṣe pe o wa ninu idajọ awọn ti wọn mọ

Ṣugbọn ti ọmọ ba jabọ latara ijanba naa tabi oyun ti o wa ni ikun rẹ, yoo wa lori nnkan ti awọn onimimọ sọ pe: Ti o ba jade ti ẹda ọmọniyan ti han nibẹ, wọn maa ka ẹjẹ rẹ lẹyin jíjáde rẹ si ẹjẹ ìbímọ, yoo gbe irun ati awẹ ju silẹ ti ọkọ rẹ si maa jina si i titi ti o fi maa mọ.

Ti ọlẹ̀ naa ba jade ti ko si tii pé ni ẹ̀dá, wọn ko nii ka si ẹjẹ ìbímọ, bi ko ṣe pe oun ni ẹjẹ ibajẹ, ko nii kọdi rẹ kuro nibi irun, tabi kuro nibi awẹ, tabi kuro nibi nnkan ti o yatọ si mejeeji

Awọn onimimọ sọ pe: Asiko ti o kere julọ ti pípé ni ẹ̀dá maa n han nibẹ ni: Ọjọ mọkanlelọgọrin; torí pe ọlẹ̀ wa ninu ikun iya rẹ

Gẹgẹ bi Abdulahi ọmọ Mas'ud- ki Ọlọhun yọnu si i- ṣe sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ba wa sọrọ, oun si ni olododo ti a sọ òdodo fun, o sọ pe: “Dajudaju ẹni kọ̀ọ̀kan ninu yin, wọn máa ko iṣẹda rẹ jọ sinu iya rẹ fun ogoji ọjọ ni omi lọgbọ lọgbọ, lẹyin naa yoo di ẹjẹ kiki bii iyẹn, lẹyin naa yoo di bááṣí ẹran bii ìyẹn, lẹ́yìn náà wọn maa gbe mọlaika kan dide si i, wọn maa pa a laṣẹ pẹlu awọn gbolohun mẹrin kan, wọn maa kọ arisiki rẹ, ati igba ti yoo lo laye, ati iṣẹ rẹ ati boya oloriburuku ni tabi oloriire ni”.

Ko rọrun lati ṣẹda rẹ ṣiwaju iyẹn, eyi ti o pọ ju ni pe pípé ni ẹ̀dá ko nii han ṣiwaju àádọ́rùn-ún ọjọ, gẹgẹ bi apakan awọn onimimọ ṣe sọ

ﺟ28: نقول: إن الحامل لا تحيض، كما قال الإمام أحمد:

"إنما تعرف النّساء الحمل بانقطاع الحيض".

والحيض -كما قال أهل العلم- خلقه الله تبارك وتعالى لحكمة غذاء الجنين في بطن أمّه، فإذا نشأ الحمل انقطع الحيض.

لكن بعض النّساء قد يستمرّ بها الحيض على عادته كما كان قبل الحمل، فهذه يحكم بأن حيضها حيضٌ صحيحٌ؛ لأنه استمر بها الحيض، ولم يتأثر بالحمل، فيكون هذا الحيض مانعًا لكلّ ما يمنعه حيض غير الحامل، وموجبًا لـما يوجبه، ومسقطًا لـما يسقطه.

والحاصل: أن الدم الّذي يخرج من الحامل على نوعين:

نوعٌ يحكم بأنه حيضٌ، وهو الّذي استمر بها كما كان قبل الحمل، فمعنى ذلك: أن الحمل لم يؤثّر عليه، فيكون حيضًا.

والنوع الثاني: دمٌ طرأ على الحمل طروءًا، إما بسببٍ حادثٍ، أو حمل شيءٍ، أو سقوطٍ من شيءٍ ونحوه، فهذه دمها ليس بحيضٍ، وإنما هو دم عرقٍ،

وعلى هذا فلا يمنعها من الصلاة، ولا من الصوم، بل هي في حكم الطاهرات.

ولكن إذا لزم من الحادث أن ينزل الولد أو الحمل الذي في بطنها فإنها على ما قال أهل العلم: إن خرج وقد تبين فيه خلق إنسانٍ فإن دمها بعد خروجه يعدّ نفاسًا، تترك فيه الصلاة والصوم، ويتجنبها زوجها حتى تطهر.

وإن خرج الجنين وهو غير مخلّقٍ فإنه لا يعتبر دم نفاسٍ، بل هو دم فسادٍ، لا يمنعها من الصلاة، ولا من الصّيام، ولا من غيرهما.

قال أهل العلم: وأقلّ زمنٍ يتبين فيه التخليق: واحدٌ وثمانون يومًا؛ لأن الجنين في بطن أمّه، كما قال عبد الله بن مسعودٍ رضي الله عنه: حدثنا رسول الله ﷺ وهو الصادق المصدوق، فقال:

«إِنَّ أَحَدَكُمْ يُجْمَعُ فِي بَطْنِ أُمِّهِ أَرْبَعِينَ يَوْمًا، ثُمَّ يَكُونُ عَلَقَةً مِثْلَ ذَلِكَ، ثُمَّ يَكُونُ مُضْغَةً مِثْلَ ذَلِكَ، ثُمَّ يُبْعَثُ إِلَيْهِ الْمَلَكُ، وَيُؤْمَرُ بِأَرْبَعِ كَلِمَاتٍ، فَيُكْتَبُ رِزْقُهُ، وَأَجَلُهُ، وَعَمَلُهُ، وَشَقِيٌّ أَوْ سَعِيدٌ» [1]،

ولا يمكن أن يخلق قبل ذلك، والغالب أن التخليق لا يتبين قبل تسعين يومًا، كما قال بعض أهل العلم.

[10] رواه البخاري، كتاب أحاديث الأنبياء، باب خلق آدم وذريته (3333)، ومسلم، كتاب القدر، باب كيفية خلق الآدمي في بطن أمه (1) (2643).