Obinrin kan ni mi, mo bi ọmọ ni ọsu kẹta lati ọdun kan sẹ́yìn, mi ko kirun titi ti mo fi mọ, wọn si ti sọ fun mi pe: O jẹ dandan fun ẹ lati kirun. Ki ni maa ṣe, emi ko mọ onka awọn ọjọ naa geerege?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Obinrin kan ni mi, mo bi ọmọ ni ọsu kẹta lati ọdun kan sẹ́yìn, mi ko kirun titi ti mo fi mọ, wọn si ti sọ fun mi pe: O jẹ dandan fun ẹ lati kirun. Ki ni maa ṣe, emi ko mọ onka awọn ọjọ naa geerege?
س29: أنا امرأةٌ أسقطت في الشهر الثالث منذ عامٍ، ولم أصلّ حتى طهرت، وقد قيل لي: كان عليك أن تصلّي. فماذا أفعل، وأنا لا أعرف عدد الأيام بالتحديد؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Nnkan ti a mọ lọdọ awọn onimimọ ni pe: Dajudaju obinrin ti oyun rẹ ba walẹ ni ọsu kẹta, ko nii kirun; nitori pe obinrin ti ọlẹ̀ inu rẹ ba bọ́ sílẹ̀ ti ẹ̀dá rẹ si ti pe, dajudaju ẹjẹ ti o ba n jade latara rẹ yoo maa jẹ ẹjẹ ibimọ, ko si nii kirun.
Awọn onimimọ sọ pe: O rọrun ki ṣiṣẹda ọlẹ̀ han ti o ba ti pe ọjọ mọkanlelọgọrin, eyi si kere si oṣu mẹta, ti o ba mọ amọdaju pe ọlẹ̀ naa jabọ ni oṣu kẹta, dajudaju nnkan ti o ṣẹlẹ si i maa jẹ ẹjẹ ibajẹ, ko nii gbe irun ju silẹ tori rẹ
Olubeere yii, o jẹ dandan fun un lati ranti nínú ẹ̀mí ara rẹ, ti ọlẹ̀ naa ba jabọ ṣiwaju ọgọrin ọjọ́, o maa san irun pada, ti ko ba mọ ọjọ meloo ni o gbe ju silẹ
O maa ṣe odiwọn rẹ, yoo si ṣe ìwádìí, yoo si san ohun ti o ba bori nínú èrò rẹ pe oun ko ki i.
ﺟ29: المعروف عند أهل العلم: أن المرأة إذا أسقطت لثلاثة أشهرٍ فإنها لا تصلّي؛ لأن المرأة إذا أسقطت جنينًا قد تبين فيه خلق إنسانٍ فإن الدم الّذي يخرج منها يكون دم نفاسٍ لا تصلّي فيه.
قال العلماء: ويمكن أن يتبين خلق الجنين إذا تم له واحدٌ وثمانون يومًا، وهذه أقلّ من ثلاثة أشهرٍ، فإذا تيقنت أنه سقط الجنين لثلاثة أشهرٍ فإن الذي أصابها يكون دم فسادٍ، لا تترك الصلاة من أجله.
وهذه السائلة عليها أن تتذكر في نفسها، فإذا كان الجنين سقط قبل الثمانين يومًا فإنها تقضي الصلاة، وإذا كانت لا تدري كم تركت؟
فإنها تقدّر، وتتحرى، وتقضي على ما يغلب عليه ظنّها أنها لم تصلّه.