Skip to content
Àwọn ọla àti àwọn ẹkọ Masalasi Anọbi, àti àwọn ìdájọ ṣíṣe àbẹ̀wò sí saare Anabi (kí ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a) àti saare àwọn ọrẹ rẹ mejeeji (kí Ọlọhun yọnu si wọn).

Àwọn ọla àti àwọn ẹkọ Masalasi Anọbi, àti àwọn ìdájọ ṣíṣe àbẹ̀wò sí saare Anabi (kí ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a) àti saare àwọn ọrẹ rẹ mejeeji (kí Ọlọhun yọnu si wọn).

Tírà náà ṣe àlàyé àwọn ọlá àti pàtàkì Mọsalasi Anọbi àti àwọn ẹkọ ṣíṣe àbẹ̀wò sí i, bákan náà ó ṣe àfihàn àwọn ẹkọ ṣíṣe àbẹ̀wò sí saare Anọbi (kí ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a) àti saare àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ méjèèjì (kí Ọlọ́hun yọ́nú sí wọn), ó sì tẹnu mọ́ pàtàkì ìfarabale àti imọra àti jíjìnnà sí àwọn iṣẹ́ àdádáalẹ lásìkò ṣíṣe àbẹ̀wò.

Èdè: lang_yo
Ẹni tí ó pèsè: lÌgbìmọ̀ Ìmọ̀ ní abẹ ìṣàkóso àlámọrí ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ní Masalasi Al-Ḥarām ni Makkah àti Masalasi An-Nabawi ni Modinah.
Ẹ̀yà: 1.0
Download PDF 452 KB

This PDF is generated automatically from the book's text; its layout may differ from the printed edition.

0%
Font size