Mo n lọ fun Umrah, mo wa kọja ni aaye ti wọn ti n gbe arami ti mọ si n ṣe nnkan oṣu, mi o wa gbe arami, mo wa wa ni Makkah titi ti mo fi mọ, mo wa gbe arami lati Makkah, njẹ eyi lẹtọọ? Tabi ki ni maa ṣe? Ki ni o jẹ dandan fun mi?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Mo n lọ fun Umrah, mo wa kọja ni aaye ti wọn ti n gbe arami ti mọ si n ṣe nnkan oṣu, mi o wa gbe arami, mo wa wa ni Makkah titi ti mo fi mọ, mo wa gbe arami lati Makkah, njẹ eyi lẹtọọ? Tabi ki ni maa ṣe? Ki ni o jẹ dandan fun mi?
س54: أنا ذاهبةٌ للعمرة، ومررت بالميقات وأنا حائضٌ، فلم أحرم، وبقيت في مكة حتّى طهرت، فأحرمت من مكة، فهل هذا جائزٌ؟ أو ماذا أفعل؟ وما يجب عليّ؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Iṣẹ yii ko lẹtọọ, ati pe obinrin ti o fẹ ṣe Umrah, ko lẹtọọ fún un ki o kọja aaye ti a ti ń gbe arami lai gbe arami, koda ki o jẹ ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu, yoo gbe arami ni ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu, arami ti o gbe si maa ni àlàáfíà.
Ẹri lori iyẹn ni pe: Asmau ọmọ Umays, iyawo Abu Bakr- ki Ọlọhun yọnu si wọn- bímọ, Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- si ti lọ si Dhul Hulayfah ti o fẹ ṣe Hajj idagbere, o wa ranṣẹ si Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pe: Bawo ni maa ṣe ṣe? O sọ pe: “Wẹ̀, ki o si wé oju ara rẹ pẹlu aṣọ kan, ki o si gbe arami”.
Ẹjẹ nnkan oṣu da gẹgẹ bii ẹjẹ ibimọ
A maa sọ fun obinrin ti o n ṣe nnkan oṣu ti o ba kọja ni aaye ti a ti ń gbe arami, ti o si fẹ ṣe Umrah tabi Hajj, a maa sọ fún un pe: Wẹ, ki o si wé oju ara rẹ pẹlu aṣọ kan, ki o si gbe arami,
Al-Istithfaar, itumọ rẹ ni pe: Yoo de aṣọ kan mọ oju ara rẹ, yoo si so o, lẹyin naa yoo gbe arami, boya pẹlu Hajj ni o tabi pẹlu Umrah, ṣugbọn ti o ba ti gbe arami wọ ti o si ti de Makkah, ko nii wa si ile Oluwa, ko si nii rọkirika rẹ titi ti yoo fi mọ
Fun idi eyi, Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ fun Aisha nigba ti o ṣe nnkan oṣu ni asiko Hajj, o sọ fun un pe: “Ṣe nnkan ti alalaaji n ṣe, yatọ si ki o rọkirika ile Oluwa titi ti waa fi mọ”, eleyii ni ẹgbawa Bukhari ati Muslim
Ninu “Sọhiihu Bukhari” bákan náà, Aisha sọ pe nigba ti oun mọ, oun rọkirika ile Oluwa, oun si sa safa ati mariwa
Eyi da lori pe ti obinrin ba gbe arami pẹlu Hajj tabi Umrah ti o si n ṣe nnkan oṣu, tabi nnkan oṣu de ba a ṣiwaju irọkirika ile Oluwa, dajudaju ko nii rọkirika ile Oluwa, ko si nii sa safa ati mariwa titi ti yoo fi mọ ti yoo si wẹ
Ṣugbọn ti o ba ti rọkirika ile Oluwa ti o si jẹ ẹni ti o mọ, lẹyin ti o wa pari irọkirika ni o wa ri nnkan oṣu, yoo tẹsiwaju, yoo si sa safa ati mariwa koda ki nnkan oṣu wa lara rẹ, yoo si ge ninu irun ori rẹ, yoo si pari Umrah rẹ; nitori pe wọn ko ṣe imọra ni majẹmu fun sisa safa ati mariwa.
ﺟ54: هذا العمل ليس بجائزٍ، والمرأة الّتي تريد العمرة لا يجوز لها مجاوزة الميقات إلا بإحرامٍ حتى لو كانت حائضًا، فإنها تحرم وهي حائضٌ، وينعقد إحرامها، ويصحّ،
والدليل لذلك: أن أسماء بنت عميسٍ زوجة أبي بكرٍ رضي الله عنهما ولدت، والنبيّ ﷺ نازلٌ في ذي الحليفة، يريد حجة الوداع، فأرسلت إلى النبيّ ﷺ: كيف أصنع؟ قال:
«اغْتَسِلِي، وَاسْتَثْفِرِي بِثَوْبٍ، وَأَحْرِمِي» [1]،
ودم الحيض كدم النّفاس.
[24] تقدم تخريجه.
فنقول للمرأة الحائض إذا مرت بالميقات، وهي تريد العمرة أو الحج نقول لها: اغتسلي، واستثفري بثوبٍ، وأحرمي،
والاستثفار معناه: أنها تشدّ على فرجها خرقةً، وتربطها، ثم تحرم، سواء بالحجّ أو بالعمرة، ولكنها إذا أحرمت ووصلت إلى مكة لا تأتي إلى البيت، ولا تطوف به حتى تطهر، ولهذا قال النبيّ ﷺ لعائشة حين حاضت في أثناء العمرة، قال لها:
«افْعَلِي مَا يَفْعَلُ الْحَاجُّ، غَيْرَ أَلَّا تَطُوفِي فِي الْبَيْتِ حَتَّى تَطْهُرِي» [2]،
هذه رواية البخاريّ ومسلمٍ، وفي «صحيح البخاريّ» أيضًا،
«ذَكَرَتْ عَائِشَةُ أَنَّهَا لَمَّا طَهُرَتْ طَافَتْ بِالْبَيْتِ، وَبِالصَّفَا وَالْمَرْوَةِ» [3]،
فدل هذا على أن المرأة إذا أحرمت بالحجّ أو العمرة وهي حائضٌ، أو أتاها الحيض قبل الطواف، فإنها لا تطوف ولا تسعى حتى تطهر وتغتسل.
[26] البخاري، كتاب العمرة، باب عمرة التنعيم (1785).
[25] رواه البخاري، كتاب الحج، باب تقضي الحائض المناسك كلها إلا الطواف بالبيت (1650)، ومسلم، كتاب الحج، باب بيان وجوه الإحرام (120) (1211).
أما لو طافت وهي طاهرٌ، وبعد أن انتهت من الطواف جاءها الحيض، فإنها تستمرّ، وتسعى ولو كان عليها الحيض، وتقصّ من رأسها، وتنهي عمرتها؛ لأنّ السعي بين الصفا والمروة لا يشترط له الطهارة.