Ìyá mi to ọmọ ọdun marundinlaadọrin, ko si bímọ lati bii ọdun mọkandinlogun, ni báyìí, ẹjẹ n da gan lara rẹ lati bii ọdún mẹ́ta, o da bii pe àìsàn ni ti o ṣe e ni àsìkò yẹn, awẹ si ni o n bọ̀ yii, ìmọ̀ràn wo ni ẹ maa gba a? Ki ni iru rẹ maa ṣe?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ìyá mi to ọmọ ọdun marundinlaadọrin, ko si bímọ lati bii ọdun mọkandinlogun, ni báyìí, ẹjẹ n da gan lara rẹ lati bii ọdún mẹ́ta, o da bii pe àìsàn ni ti o ṣe e ni àsìkò yẹn, awẹ si ni o n bọ̀ yii, ìmọ̀ràn wo ni ẹ maa gba a? Ki ni iru rẹ maa ṣe?
س33: لي والدةٌ تبلغ من العمر خمسةً وستّين عامًا، ولها مدة تسع عشرة سنةً وهي لم تأت بأطفالٍ، والآن معها نزيف دمٍ، لها مدة ثلاث سنواتٍ، وهو مرضٌ -يبدو- أتاها في تلكم الفترة، ولأنها ستستقبل الصّيام، فكيف تنصحونها؟ وكيف يتصرف مثلها؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Ìdájọ́ irú obìnrin ti ẹjẹ ti o pọ gan n jáde lara rẹ yii ni: Ki o gbe irun ju silẹ ati awẹ ni asiko iṣesi rẹ ṣiwaju iṣẹlẹ ti o ṣẹlẹ si i yii, ti o ba jẹ pe iṣesi rẹ ni pe o maa n ṣe nnkan oṣu ni ibẹrẹ gbogbo oṣu fun ọjọ mẹfa fun apẹrẹ, yoo ko ara ro lati ibẹrẹ gbogbo oṣu fun ọjọ mẹfa ti ko nii kirun tabi gba awẹ, ti o ba ti pari yoo wẹ yoo si kirun yoo si gba awẹ
Bi obìnrin yii yoo ṣe maa kirun ati awọn iru rẹ ni pe: Yoo fọ gbogbo ojú ara rẹ dáadáa, yoo wàá wé nǹkan mọ ọn, yoo si ṣe aluwala, yoo maa ṣe ìyẹn lẹyin wiwọle irun ọran-anyan, gẹgẹ bẹẹ naa ni yoo ṣe maa ṣe e ti o ba fẹ yan nafila ni igba ti o yatọ si awọn akoko awọn irun ọran-anyan
Ni iṣesi yii- nitori inira ti o wa fun un- o lẹtọọ fun un lati da irun Zuhr ati Asr papọ, ati irun Magrib ati Ishai; titi ti iṣẹ rẹ yii o fi jẹ ẹyọkan fun irun meji: Irun Zuhr ati Asr
Ẹyọkan fun meji: Irun Magrib ati Ishai. Ẹyọkan fun irun Alufajari naa, yoo waa ṣe e ni ẹẹmẹta rọ́pò ki o jẹ ẹẹmarun-un.
Maa tun un wí ni ẹẹkan sii pe: Ti o ba ti fẹ mọra yoo fọ oju ara rẹ, yoo si wé aṣọ tabi nnkan ti o jọ ọ mọ ọn títí ti nnkan ti o n jade yoo fi fuyẹ, lẹyin naa yoo ṣe aluwala, yoo ki Zuhr ni mẹrin, ati Asr ni mẹrin, Magrib ni mẹta, Ishai ni mẹrin, ati alufajari ni rakah meji, eyi n túmọ̀ si pe: ko nii din irun ku, gẹgẹ bi àwọn èèyàn kan ṣe n lero.
Ṣugbọn o lẹtọọ fun un lati da irun Zuhr ati Asr papọ, ati Magrib ati Ishai papọ, ninu ki o da Zuhr ati Asr papọ ni ti lílọ́ lára tabi títì si iwájú, gẹgẹ bẹẹ naa ni Magrib pẹlu Ishai ninu ti lílọ́ lara tabi títì si iwájú, ti o ba fẹ ṣe nafila pẹlu aluwala yii ko si ohun ti o burú nibẹ.
ﺟ33: مثل هذه المرأة التي أصابها نزيف الدم حكمها: أن تترك الصلاة والصوم مدة عادتها السابقة قبل هذا الحدث الذي أصابها، فإذا كان من عادتها أن الحيض يأتيها من أول كلّ شهرٍ لمدة ستة أيامٍ مثلًا، فإنها تجلس من أول كلّ شهرٍ مدة ستة أيامٍ لا تصلّي ولا تصوم، فإذا انقضت اغتسلت وصلت وصامت.
وكيفية الصلاة لهذه وأمثالها: أنّها تغسل فرجها غسلًا تامًّا، وتعصبه، وتتوضأ، وتفعل ذلك بعد دخول وقت صلاة الفريضة، وكذلك تفعله إذا أرادت أن تتنفل في غير أوقات فرائض.
وفي هذه الحال -ومن أجل المشقة عليها- يجوز لها أن تجمع صلاة الظّهر مع العصر، وصلاة المغرب مع العشاء؛ حتى يكون عملها هذا واحدًا للصلاتين: صلاة الظّهر، والعصر.
وواحدًا للصلاتين: صلاة المغرب، والعشاء، وواحدًا لصلاة الفجر، بدلًا من أن تعمل ذلك خمس مراتٍ تعمله ثلاث مراتٍ.
وأعيده مرةً ثانيةً، فأقول: عندما تريد الطهارة تغسل فرجها، وتعصبه بخرقةٍ أو شبهها حتى يخف الخارج، ثم تتوضأ، وتصلّي الظّهر أربعًا، والعصر أربعًا، والمغرب ثلاثًا، والعشاء أربعًا، والفجر ركعتين، أي: أنها لا تقصر، كما يتوهمه بعض العامة،
ولكن يجوز لها أن تجمع بين صلاتي الظّهر والعصر، وبين صلاتي المغرب والعشاء، الظّهر مع العصر إمّا تأخيرًا أو تقديمًا، وكذلك المغرب مع العشاء إما تقديمًا أو تأخيرًا، وإذا أرادت أن تتنفل بهذا الوضوء فلا حرج عليها.