Mo ri nǹkan oṣù mi lori irun? Ki ni maa ṣe? Njẹ maa san irun ti o jẹ ni asiko nnkan oṣu pada bí?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Mo ri nǹkan oṣù mi lori irun? Ki ni maa ṣe? Njẹ maa san irun ti o jẹ ni asiko nnkan oṣu pada bí?
س32: دخلت عليّ العادة الشهرية أثناء الصلاة، ماذا أفعل؟ وهل أقضي الصلاة عن مدة الحيض؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Ti nnkan oṣu ba ṣẹlẹ lẹyin wiwọle akoko irun- bii ki o ri nnkan oṣu lẹyin ti oorun bá yẹ àtàrí pẹlu ọgbọn iṣẹju fun apẹrẹ- lẹyin ti o ba mọra kuro nibi nnkan oṣu yoo san irun yii pada, eyi ti akoko rẹ wọle nigba ti o jẹ ẹni ti o mọ
Fun ọrọ Ọba ti ọla Rẹ ga ti O sọ pe: {Dájúdájú ìrun kíkí jẹ́ ọ̀ran-anyàn tí A fi àkókò sí fún àwọn onígbàgbọ́ òdodo}[Surah An-Nisâ': 103]
Ko nii san irun ti o jẹ ni akoko nnkan oṣu pada; fun ọrọ rẹ- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ninu hadisi ti o gun:
“Ṣe kii ṣe pe ti o ba ṣe nnkan oṣu ko nii kirun, ko si nii gba awẹ ni”.
Awọn onimimọ fi ẹnu ko lori pe dajudaju ko nii san irun ti o jẹ ni asiko nnkan oṣu pada
Ṣugbọn ti o ba mọ, ti nnkan ti o ṣẹku ninu akoko jẹ odiwọn rakah ati ju bẹẹ lọ, yoo kirun ni asiko yẹn ti o mọ nibẹ; fun ọrọ rẹ- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pe:
“Ẹnikẹni ti o ba ba rakaa kan ninu Asr ṣiwaju ki oòrùn to wọ, o ti ba Asr”.
Ti o ba mọ́ ni akoko Asr, tabi ṣiwaju yiyọ oorun, ti nnkan ti o ṣẹku ti oorun fi maa wọ̀ tàbí yọ jẹ odiwọn rakah kan, yoo ki Asr nibi ọ̀rọ̀ akọkọ, yoo si ki Alufajari nibi ọ̀rọ̀ keji
ﺟ32: إذا حدث الحيض بعد دخول وقت الصلاة -كأن حاضت بعد الزوال بنصف ساعةٍ مثلًا- فإنها بعد أن تطهر من الحيض تقضي هذه الصلاة التي دخل وقتها وهي طاهرٌ؛ لقوله تعالى:
﴿...إِنَّ ٱلصَّلَوٰةَ كَانَتۡ عَلَى ٱلۡمُؤۡمِنِينَ كِتَٰبٗا مَّوۡقُوتٗا﴾
[النساء:103].
ولا تقضي الصلاة عن وقت الحيض؛ لقوله ﷺ في الحديث الطويل:
«أَلَيْسَتْ إِذَا حَاضَتْ لَمْ تُصَلِّ، وَلَمْ تَصُمْ؟» [1]،
وأجمع أهل العلم أنها لا تقضي الصلاة التي فاتتها أثناء مدة الحيض.
[12] تقدم تخريجه.
أما إذا طهرت، وكان باقيًا من الوقت مقدار ركعةٍ فأكثر، فإنها تصلّي ذلك الوقت الذي طهرت فيه؛ لقوله ﷺ:
«مَنْ أَدْرَكَ رَكْعَةً مِنَ الْعَصْرِ قَبْلَ أَنْ تَغْرُبَ الشَّمْسُ، فَقَدْ أَدْرَكَ الْعَصْرَ» [2]،
فإذا طهرت وقت العصر، أو قبل طلوع الشمس، وكان باقيًا على غروب الشمس أو طلوعها مقدار ركعةٍ، فإنها تصلّي العصر في المسألة الأولى، والفجر في المسألة الثانية.
[13] تقدم تخريجه.