Skip to content

Obìnrin kan, lẹyin oṣu meji ninu ẹjẹ ibimọ, ati lẹyin ti o ti mọ́, o bẹrẹ si nii maa ri awọn ẹ̀kán kekere ninu ẹjẹ, njẹ yoo ja awẹ, ti ko si nii kirun bi? Abi ki ni yoo ṣe?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Obìnrin kan, lẹyin oṣu meji ninu ẹjẹ ibimọ, ati lẹyin ti o ti mọ́, o bẹrẹ si nii maa ri awọn ẹ̀kán kekere ninu ẹjẹ, njẹ yoo ja awẹ, ti ko si nii kirun bi? Abi ki ni yoo ṣe?

س24: امرأةٌ بعد شهرين من النّفاس، وبعد أن طهرت بدأت تجد بعض النّقاط الصغيرة من الدم، فهل تفطر، ولا تصلّي؟ أو ماذا تفعل؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Awọn isoro awọn obinrin nibi ẹjẹ nnkan oṣu ati ìbímọ jẹ ibudo kan ti ko si ẹni ti o le wẹ ẹ ja, ninu awọn okunfa rẹ ni: Lilo awọn ogun oni koro ti wọn maa n kọdi oyun ati ẹjẹ nnkan oṣu, awọn eniyan ko mọ iru awọn isoro ti wọn pọ yii,

Òótọ́ ni pe awọn isoro yii ko yẹ ko gbo ni nnkan ti o ti n bẹ lati igba igbedide Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- kódà o ti n bẹ lati ìgbà tí obìnrin ti n bẹ, ṣùgbọ́n pipọ rẹ bi o ṣe tó yii, ti ọmọniyan ko ri ojútùú rẹ, o jẹ nnkan ti n ba ni nínú jẹ.

Ṣugbọn òfin gbogbogboo ni pe: Ti obinrin ba ti mọ, ti o ti ri mimọ ti o daju nibi ẹjẹ nnkan oṣu ati nibi ẹjẹ ìbímọ- nnkan ti mo gba lero pẹlu mimọ nibi ẹjẹ nnkan oṣu ni: Jíjáde omi funfun, oun ni omi funfun kan ti awọn obinrin mọ ọn- gbogbo nǹkan tí o ba wa lẹyin mimọ bii omi ti o fẹ́ dudu, tabi pupa, tabi ẹ̀kán, tabi omi tútù, gbogbo eyi kii ṣe ẹjẹ nnkan oṣu, ko si nii kọdi irun ati awẹ ati ìbálòpọ̀; tori pe kii ṣe ẹjẹ nnkan oṣu,

Ummu 'Atiyyah sọ pe: A wa ko ki n ka omi pupa ati omi ti o fẹ dudu si nnkankan. Bukhari ni o gbe e jade, Abu Daud ṣe alekun: Lẹyin mimọ. Sanadu rẹ ni alaafia

Lori eyi a maa sọ pe: Gbogbo nnkan ti o ṣẹlẹ lẹyin mimọ ti o daju ninu awọn nnkan yii ko lee ko inira ba obinrin, ko lee kọdi rẹ nibi irun rẹ ati awẹ rẹ ati sisunmọ ọkọ rẹ mọ ọn, ṣugbọn o jẹ dandan lati ma kanju titi yoo fi ri mimọ;

Nitori pe apakan ninu awọn obinrin, ti ẹjẹ ba ti gbẹ lara rẹ yoo tete lọ wẹ ṣiwaju ki o to ri mimọ

Fun idi eyi awọn obinrin awọn sọhaba maa n fi Kursuf ranṣẹ si iya awọn olugbagbọ Aaisha- ki Ọlọhun yọnu si i-, o n túmọ̀ si: Owu ti ẹjẹ n bẹ nibẹ, o maa wa sọ fun wọn pe: Ẹ ma kanju titi ti ẹ fi maa ri omi funfun.

ﺟ24: مشاكل النّساء في الحيض والنّفاس بحرٌ لا ساحل له، ومن أسبابه: استعمال هذه الحبوب المانعة للحمل والمانعة للحيض، وما كان الناس يعرفون مثل هذه الإشكالات الكثيرة،

صحيحٌ أن الإشكال ما زال موجودًا من بعثة الرسول ﷺ، بل منذ وجد النّساء، ولكن كثرته على هذا الوجه الذي يقف الإنسان حيران في حلّ مشاكله أمرٌ يؤسف له.

ولكن القاعدة العامة: أن المرأة إذا طهرت، ورأت الطّهر المتيقن في الحيض وفي النّفاس -وأعني بالطّهر في الحيض: خروج القصة البيضاء، وهو ماءٌ أبيض تعرفه النّساء- فما بعد الطّهر من كدرةٍ، أو صفرةٍ، أو نقطةٍ، أو رطوبةٍ، فهذا كلّه ليس بحيضٍ، فلا يمنع من الصلاة، ولا يمنع من الصّيام، ولا يمنع من جماع الرجل لزوجته؛ لأنه ليس بحيضٍ، قالت أمّ عطية:

«كُنَّا لَا نَعُدُّ الصُّفْرَةَ وَالْكُدْرَةَ شَيْئًا»

أخرجه البخاريّ[1]، وزاد أبو داود [2]:

«بَعْدَ الطُّهْرِ»

وسنده صحيحٌ.

[6] كتاب الحيض، باب الصفرة والكدرة في غير أيام الحيض (326).

[7] كتب الطهارة، باب في المرأة ترى الصفرة والكدرة بعد الطهر (307).

وعلى هذا نقول: كلّ ما حدث بعد الطّهر المتيقن من هذه الأشياء فإنها لا تضرّ المرأة، ولا تمنعها من صلاتها وصيامها ومباشرة زوجها إياها، ولكن يجب ألّا تتعجل حتى ترى الطّهر؛

لأن بعض النّساء إذا جف الدم عنها بادرت، واغتسلت قبل أن ترى الطّهر،

ولهذا كان نساء الصحابة يبعثن إلى أمّ المؤمنين عائشة رضي الله عنها بالكرسف، يعني: القطن فيه الدم، فتقول لهن:

«لَا تَعْجَلْنَ حَتَّى تَرَيْنَ القَصَّةَ البَيْضَاءَ»[3].

[8] أخرجه البخاري معلقًا، كتاب الحيض، باب إقبال الحيض وإدباره.