Àwọn kan ninu awọn obìnrin maa n ri ẹjẹ lọ, nígbà mii o maa da fun ọjọ kan tabi ọjọ meji, lẹyin naa yoo pada, ki ni idajọ nibi iṣesi yii nibamu si awẹ ati irun ati awọn ijọsin yoku?
- التصنيف الشرعي
- الفقهالصلاةمبطلات الصلاةالفقهالصيامأحكام الصيام
السؤال
Ibeere akọkọ:
Àwọn kan ninu awọn obìnrin maa n ri ẹjẹ lọ, nígbà mii o maa da fun ọjọ kan tabi ọjọ meji, lẹyin naa yoo pada, ki ni idajọ nibi iṣesi yii nibamu si awẹ ati irun ati awọn ijọsin yoku?
س25: بعض النّساء يستمرّ معهن الدم، وأحيانًا ينقطع يومًا أو يومين، ثم يعود، فما الحكم في هذه الحال بالنّسبة للصوم والصلاة وسائر العبادات؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Nnkan ti a mọ lọdọ ọpọlọpọ ninu awọn onimimọ ni pe: Ti obinrin ba ni iṣesi, ti iṣesi rẹ wa pari, yoo wẹ, yoo si kirun, yoo si gba awẹ, nnkan ti o ba ri lẹyin ọjọ meji tabi ọjọ mẹta ko kii ṣe ẹjẹ nnkan oṣu; nitori pe ọjọ ti o kere julọ lọdọ awọn onimimọ ni ọjọ mẹ́tàlá
Apakan ninu awọn onimimọ sọ pe: Dajudaju gbogbo igba ti o ba ri ẹjẹ oun ni ẹjẹ nnkan oṣu, gbogbo igba ti o ba ti mọra kuro nibẹ o ti jẹ ẹni ti o mọ, ti ọjọ mẹ́tàlá ko ba i tii si laaarin nnkan oṣu méjèèjì.
ﺟ25: المعروف عند كثيرٍ من أهل العلم: أن المرأة إذا كان لها عادةٌ، وانقضت عادتها، فإنها تغتسل، وتصلّي، وتصوم، وما تراه بعد يومين أو ثلاثةٍ ليس بحيضٍ؛ لأن أقل الطّهر عند هؤلاء العلماء ثلاثة عشر يومًا.
وقال بعض أهل العلم: إنها متى رأت الدم فهو حيضٌ، ومتى طهرت منه فهي طاهرٌ، وإن لم يكن بين الحيضتين ثلاثة عشر يومًا.