Ewo ni o daa julọ fun obinrin: Lati ki irun ni alẹ Ramadan ni ile rẹ, tabi ni mọsalasi, pataki julọ ti awọn waasi ati awọn iranti ba wa nibẹ? Ki ni ìmọ̀ràn rẹ fun awọn obinrin ti wọn n kirun ni awọn mọsalasi?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ewo ni o daa julọ fun obinrin: Lati ki irun ni alẹ Ramadan ni ile rẹ, tabi ni mọsalasi, pataki julọ ti awọn waasi ati awọn iranti ba wa nibẹ? Ki ni ìmọ̀ràn rẹ fun awọn obinrin ti wọn n kirun ni awọn mọsalasi?
س26: أيّهما أفضل للمرأة: أن تصلّي في ليالي رمضان في بيتها، أو في المسجد، وخصوصًا إذا كان فيه مواعظ وتذكيرٌ؟ وما توجيهك للنّساء اللاتي يصلّين في المساجد؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Eyi ti o daa julọ ni ki o kirun ni ile rẹ; fun kikari ọrọ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ti o sọ pe:
“Awọn ile wọn daa julọ fun wọn”
Ati pe ìjáde obinrin ko la ninu fitina ni ọpọlọpọ igba, ki obinrin ni ile rẹ ni oore fun un ju ki o jade fun irun lọ si mọsalasi, ati pe o rọrùn lati ri àwọn waasi ati hadiisi naa ni ipasẹ kasẹẹti.
Ìmọ̀ràn mi fun awọn ti wọn n kirun ni mọsalasi ni: Ki wọn jade lati inu ile wọn ti wọn ko nii fi ẹṣọ wọn han, tabi lo lọfinda
ﺟ26: الأفضل أن تصلّي في بيتها؛ لعموم قول النبيّ ﷺ:
«وَبُيُوتُهُنَّ خَيْرٌ لَهُنَّ» [1]،
ولأن خروج النّساء لا يسلم من فتنةٍ في كثيرٍ من الأحيان، فكون المرأة تبقى في بيتها خيرٌ لها من أن تخرج للصلاة في المسجد، والمواعظ والحديث يمكن أن تحصل عليها بواسطة الشريط.
[9] رواه أبو داود، كتاب الصلاة، باب ما جاء في خروج النساء إلى المساجد (567).
وتوجيهي للاتي يصلّين في المسجد: أن يخرجن من بيوتهن غير متبرّجاتٍ بزينةٍ، ولا متطيّباتٍ.