Skip to content

Ki ni o ri si lilo awọn ogun oni koro láti dènà nǹkan oṣù; nitori gbigba awẹ pẹlu awọn eniyan?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Ki ni o ri si lilo awọn ogun oni koro láti dènà nǹkan oṣù; nitori gbigba awẹ pẹlu awọn eniyan?

س23: ما رأيك في تناول حبوب منع الدورة الشهرية؛ من أجل الصّيام مع الناس؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Emi n ṣe ikilọ kuro nibi eyi; nítorí pe inira ti o tobi ni o n bẹ nibi awọn ogun oni koro yìí, o fi ẹṣẹ rinlẹ lọdọ mi lati ọdọ awọn dokita. A maa sọ fun obinrin pe: Eyi jẹ nnkan ti Ọlọhun ti kọ lori awọn ọmọbinrin Anọbi Adam, gba tito pẹlu nnkan ti Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- kọ, gba awẹ nigba ti ko ba si idiwọ, ti idiwọ ba ti waa wa, ki o yaa já awẹ ni ẹni tí yoo yọnu si nnkan ti Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- kadara

ﺟ23: أنا أحذّر من هذا، وذلك لأن هذه الحبوب فيها مضرةٌ عظيمةٌ، ثبت عندي ذلك عن طريق الأطبّاء، ويقال للمرأة: هذا شيءٌ كتبه الله على بنات آدم، فاقنعي بما كتب الله عز وجل، وصومي حيث لا مانع، وإذا وجد المانع فأفطري، رضًى بما قدّر الله عز وجل.