"Ẹnikẹni ti o ba ṣe Hajj nitori ti Ọlọhun, tí kò ba obinrin lopọ, tí kò sì rú ofin Ọlọhun, onitọhun yoo pada sile gẹgẹ bi ọjọ ti iya rẹ̀ bi i."
- التصنيف الشرعي
- الفقهالحج والعمرةفضل الحج والعمرةالفقهالحج والعمرةمحظورات الإحرامالفقهالحج والعمرةصفة الحج
- موضوعات الحديث
- الحج والعمرةصفة الحجالأخلاقحفظ اللسان
Lati ọdọ Abu Hurairah, ki Ọlọhun yọnu si i, o sọ pe: Mo gbọ Anabi, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a, ti n sọ pe:
"Ẹnikẹni ti o ba ṣe Hajj nitori ti Ọlọhun, tí kò ba obinrin lopọ, tí kò sì rú ofin Ọlọhun, onitọhun yoo pada sile gẹgẹ bi ọjọ ti iya rẹ̀ bi i."
«مَنْ حَجَّ لِلهِ فَلَمْ يَرْفُثْ وَلَمْ يَفْسُقْ رَجَعَ كَيَوْمِ وَلَدَتْهُ أُمُّهُ».
Anabi, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a, n ṣe alaye pé ẹnikẹni ti o ba ṣe Hajj nitori ti Ọlọhun Ọba Aleke ọla, tí kò sì bá obinrin lopọ, itumọ ibalopọ ni ibasun ati awọn ohun ti o ṣiwaju rẹ̀ gẹgẹ bii ifẹnukonu ati ifarakanra, wọn si maa n túmọ̀ rẹ̀ si ọrọ buruku, tí kò sì rú ofin Ọlọhun, nípa dídá ẹ̀ṣẹ̀ àti ṣíṣe aburú. Ninu rírú ofin Ọlọhun ni ṣiṣe awọn èèwọ̀ gbígbé harami, yoo pada sile lati Hajji rẹ̀ ní ẹniti Ọlọhun ti darijin, gẹgẹ bi wọn ti n bi ọmọde lai ni ẹṣẹ kankan lọrun.
كيوم ولدته أمه: أي رجع من حجه بغير ذنوب.
Riru ofin Ọlọhun, bi o ti jẹ pe o jẹ eewọ ni gbogbo igba, o jẹ eewọ ti a kanpá mọ́ ni àsìkò Hajj, lati lè fi babara awọn iṣẹ Hajj.
A bí ènìyàn láìsí ẹ̀ṣẹ̀ kankan lọrun rẹ̀; Kò nii gbé ẹ̀ṣẹ̀ ẹlòmíràn rù.
Tira Sọhiihu ti Bukhaariy (2/ 133) (1521).
Tira Sọhiihu ti Muslim (2/ 983) (1350).
Tira Sọhiihu ti Bukhaariy (2/ 133) (1521).
Tira Sọhiihu ti Muslim (2/ 983) (1350).
Àlékún (20)
رياض الصالحين من كلام سيد المرسلين (ص358) (1274).
بهجة الناظرين شرح رياض الصالحين.
لسليم الهلالي (2/ 401).
كنوز رياض الصالحين.
لمجموعة من الباحثين (15/ 378).
شرح رياض الصالحين.
للشيخ محمد بن صالح العثيمين (5/ 321).
شرح النووي على مسلم (9/ 119).
إكمال المعلم بفوائد مسلم.
للقاضي عياض (4/ 462).
رياض الصالحين من كلام سيد المرسلين (ص358) (1274).
بهجة الناظرين شرح رياض الصالحين.
لسليم الهلالي (2/ 401).
كنوز رياض الصالحين.
لمجموعة من الباحثين (15/ 378).
شرح رياض الصالحين.
للشيخ محمد بن صالح العثيمين (5/ 321).
شرح النووي على مسلم (9/ 119).
إكمال المعلم بفوائد مسلم.
للقاضي عياض (4/ 462).
A tọ́ka sí nínú àwọn ìwé
8 Àwọn Ìwé- Ìwádìí àti ise Àlàyé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn koko ọrọ nípa Hajj àti Umrah àti Ìṣàbẹ̀wò nibamu sí Al-Qur'an àti Sunnah.التحقيق والإيضاح لكثير من مسائل الحج والعمرة والزيارة - النسخة المعتمدة«Ẹnikẹni ti o ba ṣe Hajj, tí kò ba obinrin lopọ, tí kò sì rú ofin Ọlọhun, yoo pada sile gẹgẹ bi ọjọ ti iya rẹ̀ bi i saye ni » [97].
- Nnkan ti ààyè o gba awọn ọmọde musulumi lati ma mọ ọn”Ẹni tí o ba ṣe hajj nitori Ọlọhun ti ko ba iyawo rẹ sun oorun ìfẹ́, ti ko si dá ẹ̀ṣẹ̀; yoo pada gẹgẹ bi ọjọ ti iya Rẹ bi i.
Àlékún (6)
- فضل عشر ذي الحجة«مَن حَجَّ هَذَا الْبَيْتِ فَلَمْ يَرْفُثْ وَلَمْ يَفْسُقْ رَجَعَ كَيَوْمِ وَلَدَتْهُ أُمُّهُ».
- مشروع منهاج زادكزادك 2 طالب نهائي«مَنْ حَجَّ للهِ فَلَمْ يَرْفُثْ، وَلَمْ يَفْسُقْ رَجَعَ كَيَوْمِ وَلَدَتْهُ أُمُّهُ»
- مشروع منهاج زادكزادك 2 طالب نهائي«رَجَعَ كَيَوْمَ وَلَدَتْهُ أُمُّهُ»
- منهج إعداد الدعاةالمفردة الرابعة -أركان الإسلام"من حج ولم يرفث ولم يفسق رجع كيوم ولدته أمه"
- نبراس طالب (1)1«مَنْ حَجَّ للهِ فَلَمْ يَرْفُثْ وَلَمْ يَفْسُقْ رَجَعَ كَيَوْمِ وَلَدَتْهُ أُمُّهُ»
- نبراس طالب (3)نبراس طالب 3«مَنْ حَجَّ للهِ فَلَمْ يَرْفُثْ وَلَمْ يَفْسُقْ رَجَعَ كَيَوْمَ وَلَدَتْهُ أُمُّهُ»