“Mumini ti o pe jù ni igbagbọ ni ẹni tí ìwà rẹ dara ju, ẹni tí ó loore ju ninu yin ni ẹni tí o dara ju fun awọn obinrin wọn”.
- التصنيف الشرعي
- الفضائل والآدابفقه الأخلاقالأخلاق الحميدةالفقهفقه الأسرة والمجتمعالنكاحالعشرة بين الزوجينالعقيدةالإيمان
- موضوعات الحديث
- الأخلاقحسن الخلقأحكام الأسرةحق الزوجة
- محاور التعريف بالإسلام
- محاسن الإسلاممحاسن الأخلاق
Lati ọdọ Abu Huraira- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Òjíṣẹ́ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pé:
“Mumini ti o pe jù ni igbagbọ ni ẹni tí ìwà rẹ dara ju, ẹni tí ó loore ju ninu yin ni ẹni tí o dara ju fun awọn obinrin wọn”.
«أَكْمَلُ الْمُؤْمِنِينَ إِيمَانًا أَحْسَنُهُمْ خُلُقًا، وَخَيْرُكُمْ خَيْرُكُمْ لِنِسَائِهِمْ».
Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pé èèyàn ti o pe julọ ni igbagbọ ni ẹni tí ìwà rẹ dáa, bíi títú ojú ká, ati ṣíṣe dáadáa, ati ọ̀rọ̀ rere, ati ki èèyàn má fi sùtá kan ẹlòmíràn. Mumini ti o loore julọ ni àwọn ti wọn loore julọ fun awọn obinrin wọn, gẹgẹ bii ìyàwó rẹ, ati awọn ọmọbìnrin rẹ, ati awọn arábìnrin rẹ, ati awọn mọlẹbi rẹ lóbìnrin; torí pé àwọn ni wọn ni ẹtọ si iwa dáadáa ju ninu awọn èèyàn.
....:
Ọla ti n bẹ fun iwa dáadáa, ati pe o wa ninu igbagbọ.
Iṣẹ wa ninu igbagbọ, igbagbọ maa n lékún, o si maa n dínkù.
Apọnle Isilaamu fun obìnrin, ati ṣisẹnilojukokoro lori ṣíṣe dáadáa si i.
Tira Sunanu ti baba Daud (7/ 70) (4682).
Tira Sunanu ti Tirmidhiy (2/ 454) (1162).
Tira Sunanu ti baba Daud (7/ 70) (4682).
Tira Sunanu ti Tirmidhiy (2/ 454) (1162).
Àlékún (18)
مسند أحمد ط الرسالة (12/ 364) (7402).
سلسلة الأحاديث الصحيحة وشيء من فقهها وفوائدها.
للألباني (1/ 573).
بهجة الناظرين شرح رياض الصالحين.
لسليم الهلالي (1/ 362).
شرح رياض الصالحين.
لابن عثيمين (3/ 130).
كنوز رياض الصالحين.
لمجموعة من الباحثين (5/ 234).
مسند أحمد ط الرسالة (12/ 364) (7402).
سلسلة الأحاديث الصحيحة وشيء من فقهها وفوائدها.
للألباني (1/ 573).
بهجة الناظرين شرح رياض الصالحين.
لسليم الهلالي (1/ 362).
شرح رياض الصالحين.
لابن عثيمين (3/ 130).
كنوز رياض الصالحين.
لمجموعة من الباحثين (5/ 234).
A tọ́ka sí nínú àwọn ìwé
11 Àwọn Ìwé- Nnkan ti ààyè o gba awọn ọmọde musulumi lati ma mọ ọn”“Ẹni ti o pe julọ ninu awọn mumini ni igbagbọ: Ni ẹni ti o dára julọ ninu wọn ni iwa”.
- Nnkan ti ààyè o gba awọn ọmọde musulumi lati ma mọ ọn”"«Ẹniti o pe julọ ni igbagbọ ninu awọn Mu'mini ni ẹni ti o dara julọ ni iwa."
- Nnkan ti ààyè o gba awọn ọmọde musulumi lati ma mọ ọn”«أَكْمَلُ المُؤْمِنِينَ إِيمَانًا أَحْسَنُهُمْ خُلُقًا»[178].
Àlékún (8)
- اعتقاد الأئمة الأربعةأكمل المؤمنين إيمانًا أحسنهم خلقًا....
- التمسك بالسنة النبوية وأثاره2«أكمل المؤمنين إيمانًا: أحسنهم خلقًا».
- ترجمة المقاطع المرئية - مشروع هدايات 1(أكمل المؤمنين إيماناً أحسنهم خُلقاً).
- دين الإسلام تعرضه نصوص القرآن وسنة خير الأنامعرض دين الإسلام بالأدلة النقلية(أكمل المؤمنين إيماناً أحسنهم خلقاً)[14]
- مشروع منهاج زادكزادك 2 طالب نهائي«أَكْمَلُ الْمُؤْمِنِينَ إِيمَانًا أَحْسَنُهُمْ خُلُقًا»
- مشروع منهاج زادكزادك 2 طالب نهائي«أَكْمَلُ الْمُؤْمِنِينَ إِيمَانًا أَحْسَنُهُمْ خُلُقًا».
- مشروع منهاج زادكزادك 2 طالب نهائي«أَكْمَلُ الْمُؤْمِنِينَ إِيمَانًا أَحْسَنُهُمْ خُلُقًا»
- نبراس طالب (1)1«أَكْمَلُ الْمُؤْمِنِينَ إِيمَانًا أَحْسَنُهُمْ خُلُقًا»