Skip to content
Tani o da agbaye? Taa si ni o da mi? Ati pe ki ni idi ti o fi da mi?

Tani o da agbaye? Taa si ni o da mi? Ati pe ki ni idi ti o fi da mi?

Njẹ mo wa lori oju ọna ti o tọ̀nà? Tani o da awọn sanmọ ati ilẹ ati awọn nkan ti o wa nínú mejeeji ninu awọn ẹda ti o tobi ti ìmọ̀ wa o lee gbe gbogbo rẹ tan? Tani o ṣe eto ti o munadoko yii sinu sanmọ ati ilẹ? Tani o da ọmọniyan ti o si tun fun un ni ìgbọràn ati irina ati làákàyè ti o si tun ṣe e ni ẹni ti o ni ikapa lati wa awọn imọ ati mímọ awọn ododo?

Èdè: lang_yo
Ẹni tí ó pèsè:
Ẹ̀yà: 1.1

These files are generated automatically from the book's text; their layout may differ from the printed edition.

0%
Font size