Skip to content
Bi a ṣe n ki irun (amoun mu àwòrán ni kukuru)

Bi a ṣe n ki irun (amoun mu àwòrán ni kukuru)

Àfihàn nínú iṣẹ ni ṣókí lórí bi a ṣe n ki irun, kí a lè jọ́sìn fún Ọlọhun pẹ̀lú òye, kí irun wa sì jẹ́ aṣépé nínú àwọn orígun àti àwọn májẹ̀mú rẹ̀. Bí a ṣe ń kí irun Ti a ba fẹ́ ki ìrun, ó di dandan kí a mọra kuro nibi ẹgbin kekere ati ẹgbin nla. Kí a sì ki irun pẹlu awọn aṣọ tí o mọ tí o bo ihoho wa. Bẹẹ ni kí ara wa ati aaye ikirun wa jẹ mimọ kuro nibi awọn ẹgbin. Aa dojúkọ Qiblah (ibudajukọ) O si jẹ sunnah ki a kirun kọju si gaga kan.

Èdè: lang_yo
Ẹni tí ó pèsè:
Ẹ̀yà: 2.0

These files are generated automatically from the book's text; their layout may differ from the printed edition.

0%
Font size