Ti obinrin ba mọra ní kété ti alufajari bá yọ, ǹjẹ́ o maa kóra ro ti yoo si gba awẹ ọjọ yii, ti o si maa ní awẹ ọjọ yii, àbí o maa san an padà?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ti obinrin ba mọra ní kété ti alufajari bá yọ, ǹjẹ́ o maa kóra ro ti yoo si gba awẹ ọjọ yii, ti o si maa ní awẹ ọjọ yii, àbí o maa san an padà?
س1: إذا طهرت الـمرأة بعد الفجر مباشرةً فهل تمسك وتصوم هذا اليوم، ويكون يومها لها، أو عليها قضاء ذلك اليوم؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Ti obinrin ba mọra lẹyin yíyọ alufajari, ọrọ meji ni o n bẹ fun awọn onimimọ nipa kiko ara rẹ ro ni ọjọ yẹn:
Ọrọ akọkọ: Dajudaju ikoraro yoo maa jẹ dandan fun un ni eyi ti o ṣẹku ninu ọjọ yen, ṣugbọn wọn ko nii ka a fun un, bi ko ṣe pe idapada maa jẹ dandan fun un, eleyii ni eyi ti o gbajumọ ninu oju ọna Imam Ahmad- ki Ọlọhun kẹ ẹ-
Ọ̀rọ̀ keji: Dajudaju ikoraro o nii jẹ dandan fun un ni eyi ti o ṣẹku ninu ọjọ yẹn; nitori pe o jẹ ọjọ kan ti awẹ rẹ ko nii ni alaafia nibẹ; nitori pe o jẹ ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu ni ìbẹ̀rẹ̀ ọjọ́ náà, ko si si ninu awọn alaawẹ. Ti ko ba ti wa ni alaafia, anfaani kankan ko ṣẹku fun ikoraro, ati pe akoko yii jẹ akoko kan ti ko ni ọwọ lọ́dọ̀ rẹ; nitori pe o jẹ ẹni ti a pa laṣẹ lati má gba awẹ ni akọkọ ọsan, bi ko ṣe pe gbigba awẹ rẹ jẹ eewọ fun un ni akọkọ ọsan
Awẹ ti sharia: Oun ni ikoraro kuro nibi awọn nnkan ti wọn le ba awẹ jẹ ni ti ijọsin fun Ọlọhun- Alagbara ti O gbọnngbọn- lati igba ti alufajari ba ti yọ titi ti oorun yoo fi wọ
Ọ̀rọ̀ yii- gẹgẹ bi o ṣe ri i- ni o tẹsuwọn ju ọrọ ijẹ dandan ikoraro lọ, ati pe lori ọrọ mejeeji ni idapada ọjọ yii yoo ti jẹ dandan fun un
ﺟ1: إذا طهرت المرأة بعد طلوع الفجر فللعلماء في إمساكها ذلك اليوم قولان:
القول الأول: أنه يلزمها الإمساك بقية ذلك اليوم، ولكنه لا يحسب لها، بل يجب عليها القضاء، وهذا هو المشهور من مذهب الإمام أحمد رحمه الله.
والقول الثاني: أنه لا يلزمها أن تمسك بقية ذلك اليوم؛ لأنه يومٌ لا يصحّ صومها فيه؛ لكونها في أوله حائضًا ليست من أهل الصّيام، وإذا لم يصح لم يبق للإمساك فائدةٌ، وهذا الزمن زمنٌ غير محترمٍ بالنّسبة لها؛ لأنها مأمورةٌ بفطره في أول النهار، بل محرمٌ عليها صومه في أول النهار،
والصوم الشرعيّ: هو الإمساك عن المفطّرات تعبّدًا لله عز وجل من طلوع الفجر إلى غروب الشمس.
وهذا القول -كما تراه- أرجح من القول بلزوم الإمساك، وعلى كلا القولين يلزمها قضاء هذا اليوم.