السؤال
س2: اشرح هذه الأحكام الخمسة.
"Ibeere 2: Ṣe alaye awọn idajọ maraarun yii?"
الجواب
ج:١. الواجب: وهو على وجه اللزوم، مثل الصلوات الخمس، وصيام رمضان وبر الوالدين.
- الواجب يثاب فاعله ويعاقب تاركه.
- المستحب: وهو ليس على وجه اللزوم، مثل السنن الرواتب، وقيام الليل وإطعام الطعام والسلام. ويسمى السنة والمندوب.
- المستحب يثاب فاعله ولا يعاقب تاركه.
ملاحظة مهمة:
ينبغي للمسلم عندما يسمع أن هذا الأمر سنة أو مستحب أن يبادر إلى فعله، والاقتداء بالنبي ﷺ.
- المحرم: وهو ما تركه لازم، مثل شرب الخمر، وعقوق الوالدين، وقطع الأرحام.
- المحرم يثاب تاركه ويعاقب فاعله.
- المكروه: تركه غير لازم، مثل الأخذ والإعطاء باليد الشمال، كف الثوب في الصلاة.
- المكروه يثاب تاركه ولا يعاقب فاعله.
- المباح: وهو على التخيير بين تركه وفعله، مثل أكل التفاحة وشرب الشاي، ويسمى: الجائز والحلال.
- المباح لا يثاب تاركه ولا يعاقب فاعله.
"Idahun- "
"1- Al-Wājib: Gẹgẹ bíi awọn irun ọran-anyan maraarun, ati aawẹ Ramadan ati ṣiṣe daadaa si obi mejeeji."
"- Al-Wājib, wọn maa san ẹni ti o ba ṣe e ni ẹsan, wọn si maa fi iya jẹ ẹni ti o ba gbe e ju silẹ."
"2- Al-Mustahabbu: Gẹgẹ bíi àwọn sunnah awọn Irun ọran-anyan, ati qiyāmul layli ati fifun awọn eeyan ni ounjẹ, ati sisalamọ. Wọn si tun maa n pe e ni As-Sunnah ati Al-Madūb."
"- Al-Mustahabbu, wọn maa san ẹni ti o ba ṣe e ni ẹsan, wọn o si nii fi iya jẹ ẹni tí o ba gbe e ju silẹ."
"Akiyesi pataki:"
"O tọ fun musulumi ti o ba gbọ wipe alamọri yii sunnah tabi mustahabbu ni ki o tara sasa lọ ṣe e, ki o si tun maa kọṣe Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a)."
"3- Al-Muharram: Gẹgẹ bíi mimu ọtí ati ṣiṣẹ obi mejeeji, ati jija okun ẹbi."
"- Al-Muharram, wọn maa san ẹni ti o ba gbe e ju silẹ ni ẹsan, wọn o si tun fi iya jẹ ẹni ti o ba ṣe e."
"4- Al-Makrūhu: Gẹgẹ bíi gbigba ati fifun pẹlu ọwọ osi, ati kika aṣọ ni ori irun."
"- Al-Makrūhu, wọn maa san ẹni ti o ba gbe e ju silẹ ni ẹsan bẹẹ si ni wọn o nii fi iya jẹ ẹni ti o ba ṣe e."
"5- Al-Mubāhu: Gẹgẹ bíi jijẹ eso ajara (apple) ati mimu tíì, wọn si tun maa n pe e ni: Al-Jā’iz ati Al-Halāl."
"- Al-Mubāhu, wọn o nii san ẹni ti o ba gbe e ju silẹ ni ẹsan, bẹẹ si ni wọn o nii fi iya jẹ ẹni ti o ba ṣe e."