Skip to content

السؤال

س4: ما حكم البيع والمعاملات؟

"Ibeere 3: Ki ni idajọ kata-kara ati ajọṣepọ?"

الجواب

ج:الأصل في كل البيوع والمعاملات أنها حلال إلا بعض الأنواع مما حرم الله تَعَالَى.

قال تَعَالَى:

﴿وَأَحَلَّ ٱللَّهُ ٱلۡبَيۡعَ وَحَرَّمَ ٱلرِّبَوٰاْۚ﴾

[البقرة: ٢٧٥].

"Idahun- Ìpìlẹ̀ nibi gbogbo owo ati ajọṣepọ ni pe ẹtọ ni, ayaafi awọn iran kan ninu awọn nnkan ti Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ṣe ni eewọ."

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Allāhu sì ṣe òwò ṣíṣe ní ẹ̀tọ́, Ó sì ṣe òwò èlé ní èèwọ̀}"

[Suuratul-Baqarah: 24].