Skip to content

السؤال

س1: ما هي الأحكام التكليفية الخمسة؟

"Ibeere 1: Ki ni awọn idajọ ila-nnkan-bọni-lọrun maraarun?"

الجواب

ج:١. الواجب.

  1. المستحب.
  2. المحرم.
  3. المكروه.
  4. المباح.

"Idahun- "

"1- Nnkan ti o jẹ dandan."

"2- Nnkan ti a fẹ."

"3- Nnkan ti wọn ṣe ni eewọ."

"4- Nnkan ti wọn korira."

"5- Nnkan ti wọn ṣe ni ẹ̀tọ́."