Skip to content

السؤال

س٢٠: ما أنواع الكِبْرُ المحرم؟

"Ibeere 20: Ki ni awọn iran igberaga ti o jẹ eewọ?"

الجواب

ج:١. الكِبْر على الحق، وهو رد الحق وعدم قبوله.

  1. الكِبْرُ على الناس، وهو احتقارهم والاستهانة بهم.

قال رسول الله صلى الله عليه وسلم:

«لا يَدخُلُ الجَنَّةَ مَن كان في قَلبِه مِثْقالُ ذَرَّةٍ مِن كِبْرٍ».

فقال رَجُلٌ: إنَّ الرَّجُلَ يُحِبُّ أن يَكونَ ثَوبُه حسَنًا، ونَعْلُه حسَنةً؟ قال:

«إنَّ اللهَ جَميلٌ يُحِبُّ الجَمالَ، الكِبْرُ: بَطَرُ الحَقِّ، وَغَمْطُ النَّاسِ»

رواه مسلم.

  • بَطَرُ الحَقِّ: رده
  • غَمْطُ النَّاسِ: استحقارهم.
  • الثوب الحسن والنعل الحسن ليس من الكبر.

"Idahun-1- Ṣiṣe igberaga nibi ododo, oun naa ni dida a pada ati ai gba a wọle."

  1. Ṣiṣe igberaga si awọn eeyan, oun naa ni iyẹpẹrẹ wọn, ati fifi oju kere wọn."

"Ojiṣẹ Ọlọhun -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "

"«Ko nii wọ al-Jannah, ẹni tí deedee ọmọ ina-igun ninu igberaga ba wa ni ọkan rẹ».

"Ni arakunrin kan ba sọ pe: Dajudaju ọmọkunrin a maa nífẹ̀ẹ́ si ki aṣọ rẹ o yaayi ki bata rẹ naa o si dara? O sọ pe:

"«Dajudaju Ọlọhun Ọba, Arẹwa ni, O si nífẹ̀ẹ́ si nnkan ti o ba rẹwa, nkan ti n jẹ igberaga ni: kikọ ododo, ati iyẹpẹrẹ awọn eeyan»"

Muslim ni o gba a wa.

"- Batarul Haqqi: Dida a pada"

"- Gamtun Nās: Yiyẹpẹrẹ wọn"

"- Aṣọ ti o dara ati bata ti o dara o si ninu igberaga."