السؤال
س24: ما هو الكسل؟
"Ibeere 24: Ki ni n jẹ Al-Kasal (oju riro)?"
الجواب
ج:هو التثاقل عن فعل الخير وما يجب على الإنسان فعله.
ومن ذلك: التكاسل في فعل الواجبات.
- قال الله تَعَالَى:
﴿إِنَّ ٱلۡمُنَٰفِقِينَ يُخَٰدِعُونَ ٱللَّهَ وَهُوَ خَٰدِعُهُمۡ وَإِذَا قَامُوٓاْ إِلَى ٱلصَّلَوٰةِ قَامُواْ كُسَالَىٰ يُرَآءُونَ ٱلنَّاسَ وَلَا يَذۡكُرُونَ ٱللَّهَ إِلَّا قَلِيلٗا﴾
[النساء: ١٤٢].
فينبغي للمؤمن ترك الكسل والخمول والقعود، والسعي في العمل والحركة، والجد والاجتهاد في هذه الحياة بما يرضي الله تَعَالَى.
"Idahun- Oun ni kíkàndí mọ́lẹ̀ nibi ṣiṣe iṣẹ oloore ati nnkan ti ṣiṣe rẹ jẹ dandan fun ọmọniyan."
"Ati pe ninu iyẹn ni: Ìmẹ́lẹ́ nibi ṣiṣe awọn ọran-anyan."
"Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:"
"{Dájúdájú àwọn ṣọ̀bẹ-ṣèlu mùsùlùmí ń tan Allāhu, Òun náà sì máa tàn wọ́n. Nígbà tí wọ́n bá dúró láti kírun, wọ́n á dúró (ní ìdúró) òròjú, wọn yó sì máa ṣe ṣekárími (lórí ìrun). Wọn kò sì níí ṣe (gbólóhùn) ìrántí Allāhu (lórí ìrun) àfi díẹ̀ 142}"
"[Surah An-Nisâ': 48]"
"Nitori naa o lẹ́tọ̀ọ́ fun Mu'mini gbigbe imẹlẹ ati aileṣiṣẹ, ati ijokoo tẹtẹrẹ ju silẹ, o si tun lẹ́tọ̀ọ́ fun un igbiyanju nibi iṣẹ ati lilọ bibọ ati ṣiṣe wahala ati gbigba iyanju ninu aye sibi nnkan ti yio yọ Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ninu."