Skip to content

السؤال

س٢٢: ما هي الغيبة؟

"Ibeere 22: Ki ni n jẹ Al-Gībah (Ọrọ ẹyin)?"

الجواب

ج:هي ذِكْرُ أخيك المسلم بما يكره وهو غائب.

  • قال تَعَالَى:

﴿وَلَا يَغْتَبْ بَعْضُكُمْ بَعْضًا أَيُحِبُّ أَحَدُكُمْ أَنْ يَأْكُلَ لَحْمَ أَخِيهِ مَيْتًا فَكَرِهْتُمُوهُ وَاتَّقُوا اللَّهَ إِنَّ اللَّهَ تَوَّابٌ رَحِيمٌ﴾

[الحجرات: ١٢].

"Idahun- Oun ni didarukọ ọmọ-ìyá rẹ musulumi pẹlu nnkan ti o korira ti oun ko si si nibẹ."

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Kí apá kan yín má ṣe sọ̀rọ̀ apá kan lẹ́yìn. Ṣé ọ̀kan nínú yín nífẹ̀ẹ́ sí láti jẹ ẹran-ara ọmọ ìyá rẹ̀ t’ó ti kú ni? Ẹ sì kórira rẹ̀. Ẹ bẹ̀rù Allāhu. Dájúdájú Allāhu ni Olùgba-ìronúpìwàdà, Àṣàkẹ́-ọ̀run 12}"

[Suuratul-Hujuraat 11].