Skip to content

السؤال

س١٧: ما هو الحسد؟

"Ibeere 17: Ki ni n jẹ Hasad (Keeta)?"

الجواب

ج:هو تمني زوال النعمة عن الغير أو كراهية النعمة على الغير.

  • قال تَعَالَى:

﴿وَمِن شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ﴾

[الفلق: ٥].

  • وعن أنسِ بنِ مالكٍ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ، أنَّ رسولَ اللهِ ﷺ قال:

«لا تَباغَضُوا، ولا تَحاسَدُوا، ولا تَدابَرُوا، وكُونوا -عِبادَ اللهِ- إخوانًا»

رواه البخاري ومسلم.

"Idahun- Oun ni ti tanmọọn yiyẹ idẹra kuro lọdọ ẹlomiran tabi kikorira idẹra ẹlomiran."

"Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: {Àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara 5} [Sūratul Falaq: 5]."

" Lati ọdọ Anas ọmọ Mālik - ki Ọlọhun yọnu si i - dajudaju Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - sọ pe:"

"«Ẹ ma korira ara yin, ẹ ma ṣe keeta ara yin, ẹ ma kọyin si ara yin, ẹ jẹ - ẹyin ẹrusin Ọlọhun - ọmọ-ìyá»"

"Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa. "