Skip to content

السؤال

س١٥: ما أنواع خلق المحبة؟

Ibeere ẹlẹẹkarundinlogun: Ki ni awọn iran iwa ifẹ?

الجواب

ج:محبة الله تَعَالَى.

قال تَعَالَى:

﴿وَٱلَّذِينَ ءَامَنُوٓاْ أَشَدُّ حُبّٗا لِّلَّهِ﴾

[البقرة: ١٦٥].

  • محبة الرسول صلى الله عليه وسلم.

قال ﷺ:

«والَّذي نَفْسي بِيَدِه، لا يُؤمِنُ أحدُكم حتَّى أكونَ أحبَّ إليهِ مِن والِدِه ووَلَدِه»

رواه البخاري.

محبة المؤمنين، ومحبة الخير لهم كما تحبه لنفسك.

قال النبي عَلَيْهِ الصَّلَاةُ وَالسَّلَامُ:

«لَا يُؤْمِنُ أَحَدُكُمْ حَتَّى يُحِبَّ لِأَخِيهِ مَا يُحِبُّ لِنَفْسِهِ»

"Idahun- Níní ifẹ Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga-"

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo sì le jùlọ nínú ìfẹ́ sí}."

[Suuratul-Baqarah: 24].

"Nini ifẹ ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-."

O sọ pe:

"Mo fi Ẹni ti ẹmi mi n bẹ ni ọwọ Rẹ bura, ẹnikẹni ninu yin o ni tii di olugbagbọ titi maa fi di ẹni ti o ni ifẹ si ju obi rẹ ati ọmọ rẹ lọ”.

"Bukhari ni o gba a wa. "

"Nini ifẹ awọn Mu'mini, ati nini ifẹ daadaa fun wọn gẹgẹ bi o ṣe nífẹ̀ẹ́ rẹ fun ara rẹ."

"Anabi -ki ikẹ ati ọla maa ba a- sọ pe:"

“Ẹni kan kan ninu yin o ni tii di olugbagbọ titi yoo fi fẹ fun ọmọ iya rẹ nnkan to fẹ fun ara rẹ”. "