Skip to content
Adisọkan to ni alaafia ati ohun ti o takò ó

Adisọkan to ni alaafia ati ohun ti o takò ó

Iwé apilẹkọ àkọ́kọ́ Iwe tí Ọlọla, ẹniọwọ, oní mimọ àgbà Ọpẹ ni fun Ọlọhun nikan, ikẹ ati ọla ki o lọ maa ba ẹniti ko si Anọbi kankan mọ lẹyin rẹ, ati lori awọn ara ile rẹ ati awọn saabe rẹ. Lẹ́yìn náà: Dájúdájú nígbà tí adisọkan tí ó ní àlàáfíà jẹ ìpìlẹ̀ ẹsin Islam, ati ìpìlẹ̀ ẹsin, ìdí nìyẹn ti mo fi wò ó pé o ṣe pataki lati sọrọ nipa àkòrí yii, ati kíkọ ati ṣíṣe tira láti ṣe àlàyé rẹ̀ ati íṣe afihan rẹ̀.

0%
Font size